Remove unused message 'loginproblem'
[lhc/web/wiklou.git] / languages / messages / MessagesYo.php
1 <?php
2 /** Yoruba (Yorùbá)
3 *
4 * @ingroup Language
5 * @file
6 *
7 * @author Demmy
8 */
9
10 $namespaceNames = array(
11 NS_MEDIA => 'Amóhùnmáwòrán',
12 NS_SPECIAL => 'Pàtàkì',
13 NS_TALK => 'Ọ̀rọ̀',
14 NS_USER => 'Oníṣe',
15 NS_USER_TALK => 'Ọ̀rọ̀_oníṣe',
16 NS_PROJECT_TALK => 'Ọ̀rọ̀_$1',
17 NS_IMAGE => 'Àwòrán',
18 NS_IMAGE_TALK => 'Ọ̀rọ̀_àwòrán',
19 NS_MEDIAWIKI => 'MediaWiki',
20 NS_MEDIAWIKI_TALK => 'Ọ̀rọ̀_mediaWiki',
21 NS_TEMPLATE => 'Àdàkọ',
22 NS_TEMPLATE_TALK => 'Ọ̀rọ̀_àdàkọ',
23 NS_HELP => 'Ìrànlọ́wọ́',
24 NS_HELP_TALK => 'Ọ̀rọ̀_ìrànlọ́wọ́',
25 NS_CATEGORY => 'Ẹ̀ka',
26 NS_CATEGORY_TALK => 'Ọ̀rọ̀_ẹ̀ka',
27 );
28
29 $messages = array(
30 # User preference toggles
31 'tog-underline' => 'Fàlàsí àwọn ijápọ̀:',
32 'tog-justify' => "S'àlàyé gbólóhùn ọ̀rọ̀",
33 'tog-hideminor' => "Bo àtúnse kékékèé mọ́'lẹ̀ nínú àtúnse tuntun",
34 'tog-extendwatchlist' => "Fífẹ̀ ìmójútó láti ṣ'àfihàn gbogbo àtúnṣe tó ṣẹ́lẹ̀",
35 'tog-rememberpassword' => "Sè'rántí ọ̀rọ̀ìpamí mi lórí kọmputa yi",
36 'tog-watchcreations' => "S'àfikún ojúewé tí mo dá mọ́ ìmójútó mi",
37 'tog-watchdefault' => "S'àfikún ojúewé tí mo s'àtúnse mọ́ ìmójútó mi",
38 'tog-watchmoves' => "S'àfikún ojúewé tí mo kó kúrò mọ́ ìmójútó mi",
39 'tog-watchdeletion' => "S'àfikún ojúewé tí mo parẹ́ mọ́ ìmójútó mi",
40 'tog-minordefault' => "Se àmì sí gbogbo àtúnse gẹ́gẹ́ bi kékeré lát'ìbẹ̀rẹ̀.",
41 'tog-previewontop' => "Se àyẹ̀wò kí ẹ tó s'àtúnṣe",
42 'tog-previewonfirst' => "S'àfihàn àgbéwò fún àtúnse àkọ́kọ́",
43 'tog-nocache' => "D'ènà fífi ojúewé pamọ́",
44 'tog-enotifwatchlistpages' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími tí ojúewé tí mò ún mójútó bá yípadà',
45 'tog-enotifusertalkpages' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími tí ojúewé ẹnitínse mi bá yípadà',
46 'tog-enotifminoredits' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími bákannà fún àtúnse kékékèé sí ojúewé',
47 'tog-shownumberswatching' => "S'àfihàn iye àwọn ẹnitínse tí wọn ún mójútó",
48 'tog-watchlisthideown' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe mi nínú ìmójútó',
49 'tog-watchlisthidebots' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe bot nínú ìmójútó',
50 'tog-watchlisthideminor' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe kéékèké nínú ìmójútó',
51 'tog-ccmeonemails' => 'Ìfiránṣẹ́ sími àwọn àwòkọ àwọn e-mail tí mo firánṣẹ́ sí àwọn oníṣe míràn',
52 'tog-showhiddencats' => "Ṣ'àfihàn àwọn ẹ̀ka tó pamọ́",
53
54 'underline-always' => 'Nígbà gbogbo',
55
56 # Dates
57 'sunday' => 'Ọjọ́àìkú',
58 'monday' => 'Ọjọ́ajé',
59 'tuesday' => 'Ọjọ́ìsẹ́gun',
60 'wednesday' => 'Ọjọ́rú',
61 'thursday' => 'Ọjọ́bọ̀',
62 'friday' => 'Ọjọ́ẹtì',
63 'saturday' => 'Ọjọ́àbámẹ́ta',
64 'sun' => 'Àìkú',
65 'mon' => 'Ajé',
66 'tue' => 'Ìṣẹ́gun',
67 'wed' => 'Rú',
68 'thu' => 'Bọ̀',
69 'fri' => 'Ẹtì',
70 'sat' => 'Àbámẹ́ta',
71 'january' => 'January',
72 'february' => 'February',
73 'march' => 'March',
74 'april' => 'April',
75 'may_long' => 'May',
76 'june' => 'June',
77 'july' => 'July',
78 'august' => 'August',
79 'september' => 'September',
80 'october' => 'October',
81 'november' => 'November',
82 'december' => 'December',
83 'january-gen' => 'January',
84 'february-gen' => 'February',
85 'march-gen' => 'March',
86 'april-gen' => 'April',
87 'may-gen' => 'May',
88 'june-gen' => 'June',
89 'july-gen' => 'July',
90 'august-gen' => 'August',
91 'september-gen' => 'September',
92 'october-gen' => 'October',
93 'november-gen' => 'November',
94 'december-gen' => 'December',
95 'jan' => 'Jan',
96 'feb' => 'Feb',
97 'mar' => 'Mar',
98 'apr' => 'Apr',
99 'may' => 'May',
100 'jun' => 'Jun',
101 'jul' => 'Jul',
102 'aug' => 'Aug',
103 'sep' => 'Sep',
104 'oct' => 'Oct',
105 'nov' => 'Nov',
106 'dec' => 'Dec',
107
108 # Categories related messages
109 'pagecategories' => '{{PLURAL:$1|Ẹ̀ka|Àwọn ẹ̀ka}}',
110 'category_header' => 'Àwọn ojúewé nínú ẹ̀ka "$1"',
111 'category-empty' => "''Lọ́wọ́lọ́wọ́ ẹ̀ka yìí kò ní ojúewé tàbí amóhùnmáwòrán kankan.''",
112 'hidden-categories' => '{{PLURAL:$1|Ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀|Áwọn ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀}}',
113 'hidden-category-category' => 'Àwọn ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀', # Name of the category where hidden categories will be listed
114 'listingcontinuesabbrev' => 'tẹ̀síwájú',
115
116 'about' => 'Nípa',
117 'newwindow' => '(yíò sí nínú fèrèsè tuntun)',
118 'cancel' => "Fa'gilé",
119 'qbfind' => 'Wá rí',
120 'qbedit' => 'Àtúnṣe',
121 'qbpageoptions' => 'Ojúewé yi',
122 'qbmyoptions' => 'Àwọn ojúewé mi',
123 'qbspecialpages' => 'Àwọn ojúewé pàtàkì',
124 'moredotdotdot' => 'Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́...',
125 'mypage' => 'Ojúewé mi',
126 'mytalk' => 'Ọ̀rọ̀ mi',
127 'anontalk' => 'Ọ̀rọ̀ fún IP yí',
128 'navigation' => 'Atọ́ka',
129 'and' => 'àti',
130
131 'errorpagetitle' => 'Àsìse',
132 'returnto' => 'Padà sí $1.',
133 'tagline' => "Lát'ọwọ́ {{SITENAME}}",
134 'help' => 'Ìrànlọ́wọ́',
135 'search' => 'Ṣe àwáàrí',
136 'searchbutton' => 'Ṣe àwáàrí',
137 'go' => 'Ó yá',
138 'searcharticle' => 'Ó yá',
139 'history' => 'Ìtàn ojúewé',
140 'history_short' => '
141 Ìtàn',
142 'updatedmarker' => 'jẹ́ títúnṣe lẹ́yìn àbẹ̀wò mi',
143 'printableversion' => 'Títẹ̀ sí ìwé',
144 'permalink' => 'Ìjápọ̀ tíkòníyípadà',
145 'print' => 'Tẹ̀síìwé',
146 'edit' => 'Àtúnṣe',
147 'create' => "Ṣè'dá",
148 'editthispage' => "S'àtúnṣe ojúewé yi",
149 'create-this-page' => "Ṣè'dá ojúewé yìí",
150 'delete' => 'Paarẹ́',
151 'deletethispage' => 'Pa ojúewé yi rẹ́',
152 'protect' => 'Dábòbò',
153 'protectthispage' => 'Dá àbò bo ojúewé yìí',
154 'unprotect' => 'Mú àbò kúrò',
155 'unprotectthispage' => 'Mú àbò kúrò lórí ojúewé yìí',
156 'newpage' => 'Ojúewé tuntun',
157 'talkpage' => 'Kábárawasọ̀rọ̀ nípa ojúewé yi',
158 'talkpagelinktext' => 'Kábárawasọ̀rọ̀',
159 'specialpage' => 'Ojúewé Pàtàkì',
160 'personaltools' => 'Àwọn irinṣẹ́ àdáni',
161 'postcomment' => 'Ṣe àwísọ',
162 'talk' => 'Ìfọ̀rọ̀wérọ̀',
163 'views' => 'Àwọn ìwò',
164 'toolbox' => 'Àpótí irinṣẹ',
165 'userpage' => 'Wo ojúewé oníṣe',
166 'projectpage' => 'Wo ojúewé iṣẹ́ọwọ́',
167 'imagepage' => 'Wo ojúewé amóhùnmáwòrán',
168 'mediawikipage' => 'Wo ojúewé ìránṣẹ́',
169 'templatepage' => 'Wo ojúewé àdàkọ',
170 'viewhelppage' => 'Wo ojúewé ìrànlọ́wọ́',
171 'categorypage' => 'Wo ojúewé ẹ̀ka',
172 'viewtalkpage' => 'Wo ìfọ̀rọ̀wérọ̀',
173 'otherlanguages' => 'Àwọn èdè míràn',
174 'redirectedfrom' => '(Àtúnjúwe láti $1)',
175 'redirectpagesub' => 'Ojúewé àtúnjúwe',
176 'lastmodifiedat' => 'Ọjọ́ tí a ṣe àtunṣe ojúewé yi gbẹ̀yìn ni $2, $1.', # $1 date, $2 time
177 'viewcount' => 'A ti wo ojúewé yi ni {{PLURAL:$1|ẹ̀kan péré|iye ìgbà $1}}.',
178 'protectedpage' => 'Ojúewé aláàbò',
179 'jumptonavigation' => 'atọ́ka',
180 'jumptosearch' => "
181 ṣ'àwáàrí",
182
183 # All link text and link target definitions of links into project namespace that get used by other message strings, with the exception of user group pages (see grouppage) and the disambiguation template definition (see disambiguations).
184 'aboutsite' => 'Nípa {{SITENAME}}',
185 'aboutpage' => 'Project:Nípa',
186 'copyright' => 'Gbogbo ohun inú ibí yi wà lábẹ́ $1.',
187 'copyrightpagename' => '{{SITENAME}} ẹ̀tọ́àwòkọ',
188 'copyrightpage' => '{{ns:project}}:Ẹ̀tọ́àwòko',
189 'currentevents' => 'Ìròhìn nísinsìnyí',
190 'currentevents-url' => 'Project:Ìròhìn nísinsìnyí',
191 'disclaimers' => 'Ikìlọ̀',
192 'disclaimerpage' => 'Project:Ìkìlọ̀ gbogbo',
193 'edithelp' => "Ìrànlọ́wọ́ láti s'àtúnṣe",
194 'edithelppage' => 'Help:Àtúnṣe',
195 'mainpage' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
196 'mainpage-description' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
197 'portal' => 'Èbúté àwùjọ',
198 'portal-url' => 'Project:Èbúté Àwùjọ',
199
200 'badaccess-group0' => "A kò gbàyín l'áyè l'áti ṣe ohun tí ẹ bèrè fún.",
201
202 'ok' => 'OK',
203 'youhavenewmessages' => 'Ẹ ní $1 ($2).',
204 'newmessageslink' => 'ìfọ̀rọ̀ránsẹ́ tuntun',
205 'newmessagesdifflink' => 'àtúnṣe ìgbẹ̀yìn',
206 'youhavenewmessagesmulti' => 'Ẹ ní ìfọ̀rọ̀ránsẹ́ tuntun ni $1',
207 'editsection' => "s'àtúnṣe",
208 'editold' => "s'àtúnṣe",
209 'viewsourceold' => 'wo àmìọ̀rọ̀',
210 'editsectionhint' => 'Abala àtúnṣe: $1',
211 'showtoc' => 'fihàn',
212 'hidetoc' => 'bòmọ́lẹ̀',
213 'thisisdeleted' => 'Wo tàbí múpadà $1?',
214 'viewdeleted' => 'Wo $1?',
215 'restorelink' => '{{PLURAL:$1|àtúnṣe tóparẹ́ kan|àtúnṣe tóparẹ́ $1}}',
216 'site-rss-feed' => '$1 RSS Feed',
217 'site-atom-feed' => '$1 Atom Feed',
218
219 # Short words for each namespace, by default used in the namespace tab in monobook
220 'nstab-main' => 'Àyọkà',
221 'nstab-user' => 'Ojúewé oníṣe',
222 'nstab-media' => 'Ojúewé amóhùnmáwòrán',
223 'nstab-special' => 'Pàtàkì',
224 'nstab-project' => 'Ojúewé iṣẹ́ọwọ́',
225 'nstab-image' => 'Faili',
226 'nstab-mediawiki' => 'Ìfọ̀rọ̀ránsẹ',
227 'nstab-template' => 'Àdàkọ',
228 'nstab-help' => 'Ojúewé ìrànlọ́wọ́',
229 'nstab-category' => 'Ẹ̀ka',
230
231 # Main script and global functions
232 'nosuchaction' => 'Kò sí irú ìgbéṣe báun',
233 'nosuchactiontext' => 'Ìgbéṣe tí URL yìí tọ́kasí kò ní ìdámọ̀ lórí wiki yìí',
234 'nosuchspecialpage' => 'Kò sí irú ojúewé pàtàkì báun',
235 'nospecialpagetext' => "<big>'''Ẹ tọrọ ojúewé pàtàkì tólòdì.'''</big>
236
237 Àkójọ àwọn ojúewé pàtàkì tóbámu wà ní [[Special:SpecialPages|{{int:specialpages}}]].",
238
239 # General errors
240 'error' => 'Àsìṣe',
241 'missingarticle-diff' => '(Ìyàtọ̀: $1, $2)',
242 'filecopyerror' => 'Àwòkọ faili "$1" sí "$2" kò ṣe é ṣe.',
243 'filerenameerror' => 'Àtúnsọlórúkọ faili "$1" sí "$2" kò ṣe é ṣe.',
244 'filedeleteerror' => 'Ìparẹ́ faili "$1" kò ṣe é ṣe.',
245 'directorycreateerror' => 'Ìwé-ìjúwe "$1" kò ṣe é ṣe.',
246 'filenotfound' => 'Kò le é ṣe àwáàrí faili "$1".',
247 'badtitle' => 'Àkọ́lé burúkú',
248 'viewsource' => 'Àfihàn ọ̀rọ̀àmì',
249 'viewsourcefor' => 'fún $1',
250 'protectedpagetext' => 'A ti se àtìpa ojúewé yi. Ẹ kò le se àtúnṣe.',
251 'viewsourcetext' => 'Ẹ lè wo ati ẹ lè se àwòkọ ọ̀rọ̀àmì ojúewé yi:',
252 'ns-specialprotected' => 'Àtúnṣe kò ṣe é ṣe sí àwọn ojúewé pàtàkì.',
253 'titleprotected' => "This title has been protected from creation by [[User:$1|$1]]. The reason given is ''$2''.",
254
255 # Login and logout pages
256 'logouttitle' => 'Ibọsóde oníṣe',
257 'logouttext' => "<strong>Ẹ ti bọ́sọ́de.</strong>
258
259 Ẹ le tẹ̀síwájú sí ní lo {{SITENAME}} láìmorúkọ yín, tàbí kí ẹ [[Special:UserLogin|padà wọlé]] bí ẹnikanan tàbí ẹlòmíràn.
260 Àkíyèsí wípé àwọn ojúewé kan le hàn b'ígbà tójẹ́pé ẹ sì wọlé títí tí ẹ ó fi jọ̀wọ́ àdìmú (cache) browser yín.",
261 'welcomecreation' => "== Ẹ kú àbọ̀, $1! ==
262
263 A ti fi orúkọ yín s'ílẹ̀. Ẹ mọ́ gbàgbé l'áti s'àtúnṣe àwọn ìfẹ́ràn {{SITENAME}} yín.",
264 'loginpagetitle' => 'Ìwọlé oníṣe',
265 'yourname' => 'Orúkọ oníṣe (username):',
266 'yourpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́:',
267 'yourpasswordagain' => 'Tẹkíkọ ọ̀rọ̀ìpamọ́ lẹ́ẹ̀kansí:',
268 'remembermypassword' => "Sè'rántí ọ̀rọ̀ìpamí mi lórí kọmputa yi (cookies)",
269 'login' => 'Ìwọlé',
270 'nav-login-createaccount' => 'Ìwọlé / Ìforúkọ sílẹ̀',
271 'userlogin' => 'Ìwọlé / ìforúkọ sílẹ̀',
272 'logout' => 'Ìbọ́sóde',
273 'userlogout' => 'Ìbọ́sóde',
274 'notloggedin' => "Ẹ kò tí w'ọlé",
275 'nologin' => 'Ṣé ẹ fẹ́ wọlé? $1.',
276 'nologinlink' => 'Ẹ fi orúkọ sílẹ̀',
277 'createaccount' => 'Ẹ fi orúkọ sílẹ̀',
278 'gotaccount' => 'Ṣé ẹ ti ní àpamọ́ tẹ́lẹ̀? $1.',
279 'gotaccountlink' => "Ẹ w'ọlé",
280 'createaccountmail' => 'pẹ̀lú e-mail',
281 'badretype' => 'Àwọn ọ̀rọ̀ìpamọ́ tí ẹ kọ kò jọ ra wọn.',
282 'youremail' => 'E-mail:',
283 'username' => 'Orúkọ oníṣe:',
284 'uid' => 'Nọmba ìdámọ̀ fún ẹnitínṣe:',
285 'yourrealname' => 'Orúkọ ganangan:',
286 'yourlanguage' => 'Èdè:',
287 'yournick' => 'Ìtọwọ́bọ̀:',
288 'badsiglength' => 'Ìtọwọ́bọ̀ yín ti gùnjù.
289 Kò gbodọ̀ ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà|àwọn àmìlẹ́tà}} $1 lọ.',
290 'email' => 'E-mail',
291 'loginerror' => 'Àsìṣe ìwọlé',
292 'prefs-help-email-required' => 'E-mail ṣe dandan.',
293 'noname' => 'Ẹ kò tọ́kasí orúkọ oníṣe tó ní ìbámu.',
294 'loginsuccesstitle' => 'Ìwọlé ti yọrí sí rere',
295 'loginsuccess' => "'''Ẹ ti wọlé sínú {{SITENAME}} gẹ́gẹ́ bi \"\$1\".'''",
296 'nosuchuser' => 'Kò sí oníṣe kankan pẹ̀lú orúkọ "$1".
297 Ẹ yẹ lẹ́tà yín wò, tàbí [[Special:Userlogin/signup|kí ẹ s\'èdá àpamọ́ tuntun]].',
298 'nouserspecified' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ tọ́kasí orúkọ oníṣe kan.',
299 'wrongpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tí ẹ kìbọ́ kòtọ́.
300 Ẹ jọ̀wọ́ ẹ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kansí.',
301 'passwordtooshort' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín jẹ́ aláìtọ́ tàbí ó kúrú ju bóṣe yẹ lọ.
302 Kò gbọ́dọ̀ dín ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà kan|àmìlẹ́tà $1}} lọ, kí ó sì yàtọ̀ sí oríkọoníṣe yín.',
303 'mailmypassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun sí e-mail',
304 'noemail' => 'Kò sí àkọsílẹ̀ ojúọ̀nà e-mail fún oníṣe "$1".',
305 'emailauthenticated' => 'Ojúọ̀nà e-mail yín fidájú ní ago $3 ọjọ́ $2.',
306 'emailconfirmlink' => 'Ẹ ṣe ìmúdájú ojúọ̀nà e-mail yín',
307 'accountcreated' => 'Ẹ ti fi orúkọ sílẹ̀',
308 'accountcreatedtext' => "A ti ṣ'èdá àpamọ́ oniṣe fún $1.",
309 'createaccount-title' => 'Ìforúkọ sílẹ̀ fún {{SITENAME}}',
310 'loginlanguagelabel' => 'Èdè: $1',
311
312 # Password reset dialog
313 'resetpass' => 'Àtúntò ọ̀rọ̀ìpamọ́ àpamọ́',
314 'resetpass_header' => 'Àtúntò ọ̀rọ̀ìpamọ́',
315 'resetpass_success' => 'Ìyípadà ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín ti já sí rere! Ẹ̀ ún wọlé lọ́wọ́...',
316
317 # Edit page toolbar
318 'link_sample' => 'Àkọlé ìjápọ̀',
319 'media_tip' => 'Ìjápọ̀ faili',
320
321 # Edit pages
322 'summary' => 'Àkótán',
323 'minoredit' => 'Àtúnṣe kékeré nìyí',
324 'watchthis' => "M'ójútó ojúewé yìí",
325 'savearticle' => 'Ẹ fi pamọ́',
326 'preview' => 'Àyẹ̀wò',
327 'showpreview' => 'Àyẹ̀wò',
328 'showdiff' => 'Àfihàn àwọn àyípadà',
329 'anoneditwarning' => "'''Ìkìlọ̀:''' Ẹ ò tíì wọlé.
330 Á ṣe àkọsílẹ̀ ojúọ̀nà IP yín ninu ìwé àtúnṣe ojúewé yìí.",
331 'blockedtitle' => 'Ìdènà sí oníṣe',
332 'whitelistedittitle' => "Ìwọlé ṣe dandan láti ṣ'àtúnṣe",
333 'whitelistedittext' => "Ẹ gbọ́dọ̀ $1 láti ṣ'àtúnṣe àwọn ojúewé.",
334 'confirmedittitle' => "Ìmúdájú E-mail ṣe dandan láti ṣ'àtúnṣe",
335 'nosuchsectiontitle' => 'Kò sí irú abala báun',
336 'loginreqtitle' => "Ẹ gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ w'ọlé ná",
337 'loginreqlink' => 'ìwọlé',
338 'loginreqpagetext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ $1 láti wo àwọn ojúewé míràn.',
339 'accmailtitle' => 'Ti fi ọ̀rọ̀ìpamọ́ ránṣẹ́.',
340 'accmailtext' => 'A ti fi ọ̀rọ̀ìpamọ́ fún "$1" ránṣẹ́ sí $2.',
341 'newarticle' => '(Tuntun)',
342 'newarticletext' => "Ẹ ti tẹ̀lé ìjápọ̀ mọ́ ojúewé tí kò sí.
343 Láti dá ojúewé yí ẹ bẹ̀rẹ̀ síní tẹ́kọ sí inú àpótí ìsàlẹ̀ yí (ẹ wo [[{{MediaWiki:Helppage}}|ojúewé ìrànlọ́wọ́ ]] fun ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ).
344 T'óbá sepé àsìse ló gbé yin dé bi, ẹ kọn bọ́tìnì ìpadàsẹ́yìn.",
345 'note' => '<strong>Àkíyèsí:</strong>',
346 'session_fail_preview' => '<strong>Àforíjìn! A kò le gbésẹ̀ àtúnṣe yín nítorí ìpòfo data ìsinsìyí.
347 Ẹ jọ̀wọ́ ẹ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan si.
348 Tí kò bá sì tún ṣiṣẹ́, ẹ gbìyànjú láti [[Special:UserLogout|bọ̀sòde]] kí ẹ sì padá wọlé.</strong>',
349 'editing' => 'Àtúnṣe sí $1',
350 'yourdiff' => 'Àwọn ìyàtọ̀',
351 'copyrightwarning' => 'Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kíyèsi wípé gbogbo àwọn àfikún sí {{SITENAME}} jẹ́ bẹ̀ lábẹ́ $2 (Ẹ wo $1 fún ẹkunrẹrẹ).
352 Tí ẹ kò bá fẹ́ kí ìkọọ́lẹ̀ yín ó jẹ́ títúnṣe tàbí kì ó jẹ́ pípìn kiri lọ́ná tí kò wù yín, ẹ mọ́ mù wá síbí.<br />
353 Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín, tàbí ẹ wòókọ láti agbègbè ìgboro tàbí irú ìtìlẹ́yín ọ̀fẹ́ bíi bẹ́ẹ̀.
354 <strong>Ẹ MỌ́ MÚ IṢẸ́ TÓ NÍ Ẹ̀TỌ́ÀWÒKỌ SÍLẸ̀ LÁÌ GBÀṢẸ!</strong>',
355 'template-protected' => '(aláàbò)',
356 'template-semiprotected' => '(aláàbò díẹ̀)',
357 'recreate-deleted-warn' => "'''Ìkìlọ̀: Ẹ̀ ún ṣ'èdá ojúewé tí a ti parẹ́ tẹ́lẹ̀.'''
358
359 Ẹ gbọ́dọ̀ gberò bóyá ó bójúmu láti tẹ̀síwájú pẹ̀lú àtúnṣe ojúewé yìí.
360 Àkọsílẹ̀ ìparẹ́ nìyí fún ìrọ̀rùn:",
361
362 # Account creation failure
363 'cantcreateaccounttitle' => 'Ìforúkọsílẹ̀ kò se é se',
364
365 # History pages
366 'currentrev' => 'Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí',
367 'revisionasof' => 'Àtúnyẹ̀wò ní $1',
368 'revision-info' => "Àtúnyẹ̀wò ní $1 l'átọwọ́ $2",
369 'previousrevision' => '← Àtúnyẹ̀wò tópẹ́ju',
370 'nextrevision' => 'Àtúnyẹ̀wò tótuntunju →',
371 'currentrevisionlink' => 'Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí',
372 'cur' => 'lọ́wọ́',
373 'next' => 'tókàn',
374 'last' => 'tẹ́lẹ̀',
375 'page_first' => 'àkọ́kọ́',
376 'page_last' => 'tógbẹ̀yìn',
377 'deletedrev' => '[tiparẹ́]',
378 'historyempty' => '(òfo)',
379
380 # Revision feed
381 'history-feed-title' => 'Ìtàn àtúnyẹ̀wò',
382 'history-feed-description' => 'Ìtàn àtúnyẹ̀wò fún ojúewé yìí ní orí wiki',
383 'history-feed-item-nocomment' => '$1 $2', # user at time
384
385 # Revision deletion
386 'rev-delundel' => 'fihàn/bòmọ́lẹ̀',
387 'pagehist' => 'Ìtàn ojúewé',
388 'deletedhist' => 'Ìtàn ìparẹ́',
389 'revdelete-summary' => 'àkótán àtúnṣe',
390 'revdelete-uname' => 'orúkọ oníṣe',
391
392 # Diffs
393 'editundo' => 'dápadà',
394 'diff-movedto' => 'tiyípò sí $1',
395
396 # Search results
397 'searchresults' => 'Àwọn èsì àwáàrí',
398 'searchresults-title' => 'Àwọn èsì àwáàrí fún $1',
399 'searchsubtitle' => 'Ẹ ṣ\'àwáàrí fun \'\'\'[[:$1]]\'\'\' ([[Special:Prefixindex/$1|gbogbo ojúewé tó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lu "$1"]] | [[Special:WhatLinksHere/$1|gbogbo ojúewé tó jápọ̀ mọ́ "$1"]])',
400 'searchsubtitleinvalid' => "Ẹ ṣ'àwáàrí fun '''$1'''",
401 'noexactmatch' => "'''Kò sí ojúewé pẹ̀lú àkọlé \"\$1\".'''
402 Ẹ le [[:\$1|ṣ'èdá ojúewé yìí]].",
403 'noexactmatch-nocreate' => "'''Kò sí ojúewé pẹ̀lú àkọlé \"\$1\".'''",
404 'prevn' => 'titẹ́lẹ̀ $1',
405 'nextn' => 'tókàn $1',
406 'viewprevnext' => 'Ẹ wo ($1) ($2) ($3)',
407 'search-relatedarticle' => 'Tóbáramu',
408 'searchrelated' => 'tóbáramu',
409 'searchall' => 'gbogbo',
410 'powersearch' => 'Ṣe àwáàrí',
411 'powersearch-legend' => 'Àwáàrí gíga',
412 'powersearch-ns' => 'Àwáàrí nínú orúkọàyè:',
413 'powersearch-redir' => 'Àkójọ àwọn àtúnjúwe',
414 'powersearch-field' => 'Àwáàrí fún',
415
416 # Preferences page
417 'preferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn',
418 'mypreferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn mi',
419 'prefs-edits' => 'Iye àwọn àtúnṣe:',
420 'prefsnologin' => 'Ẹ kò tíì wọlé',
421 'prefsnologintext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ <span class="plainlinks">[{{fullurl:Special:Userlogin|returnto=$1}} wọlé]</span> láti to àwọn ìfẹ́ràn oníṣe.',
422 'changepassword' => 'Ìyípadà ọ̀rọ̀ìpamọ́',
423 'skin' => 'Skin (Àwọ̀)',
424 'dateformat' => 'Ìṣájúètò ọjọ́',
425 'datedefault' => 'Kò sí ìfẹ́ràn',
426 'datetime' => 'Ọjọ́ àti àkókò',
427 'prefs-personal' => 'Ọ̀rọ̀ nípa oníṣe',
428 'prefs-rc' => 'Àwọn àtúnṣe tuntun',
429 'prefs-watchlist' => 'Ìmójútó',
430 'prefs-watchlist-days' => 'Ọjọ́ láti fihàn nínú ìmójútó:',
431 'saveprefs' => 'Ìfipamọ́',
432 'resetprefs' => 'Palẹ̀mọ́ àwọn àtúnṣe tí kò sì ní ìpamọ́',
433 'oldpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ titẹ́lẹ̀:',
434 'newpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun:',
435 'searchresultshead' => 'Àwáàrí',
436 'savedprefs' => 'Àwọn ìfẹ́ràn yín ti wà nípamọ́.',
437 'prefs-searchoptions' => 'Àwọn ìyàn àwáàrí',
438 'prefs-namespaces' => 'Àwọn orúkọàyè',
439 'files' => 'Àwọn faili',
440
441 # Groups
442 'group' => 'Àkójọpọ̀:',
443 'group-autoconfirmed' => 'Àwọn oníṣe ìmúdájú fúnrawọn',
444 'group-sysop' => 'Àwọn alámùójútó',
445
446 'grouppage-user' => '{{ns:project}}:Àwọn oníṣe',
447 'grouppage-autoconfirmed' => '{{ns:project}}:Àwọn oníṣe ìmúdájú fùnrawọn',
448 'grouppage-bot' => '{{ns:project}}:Àwọn Bot',
449 'grouppage-sysop' => '{{ns:project}}:Àwọn alámùójútó',
450
451 # Recent changes
452 'recentchanges' => 'Àwọn àtúnṣe tuntun',
453 'rcnote' => "Lábẹ́ yìí ni {{PLURAL:$1|àtúnṣe '''kan'''|àwọn àtúnṣe '''$1'''}} tó kẹ̀yìn ní ọjọ́ '''$2''' sẹ́yìn, ní ago $5, ọjọ́ $4.",
454 'rcshowhideminor' => '$1 àwọn àtúnṣe kékéèké',
455 'rcshowhidebots' => '$1 àwọn bot',
456 'rcshowhideliu' => '$1 àwọn oníṣe tótiwọlé',
457 'rcshowhideanons' => '$1 àwọn oníṣe aláìlórúkọ',
458 'rcshowhidemine' => '$1 àwọn àtúnṣe mi',
459 'rclinks' => "Ṣ'àfihàn àtúnṣe $1 tó kẹ̀yìn ní ọjọ́ $2 sẹ́yìn<br />$3",
460 'diff' => 'ìyàtọ̀',
461 'hist' => 'ìtàn',
462 'hide' => 'Ìbòmọ́lẹ̀',
463 'show' => 'Àfihàn',
464 'minoreditletter' => 'k',
465 'newpageletter' => 'T',
466 'boteditletter' => 'b',
467 'rc_categories_any' => 'Èyíkéyìí',
468 'newsectionsummary' => '/* $1 */ abala tuntun',
469
470 # Recent changes linked
471 'recentchangeslinked' => 'Àtúnṣe tó báramu',
472 'recentchangeslinked-title' => 'Àtúnṣe tó báramu mọ́ "$1"',
473 'recentchangeslinked-page' => 'Orúkọ ojúewé:',
474
475 # Upload
476 'upload' => 'Ìrùsókè faili',
477 'uploadbtn' => 'Ìrùsókè faili',
478 'reupload' => 'Àtún-rùsókè',
479 'uploadnologin' => 'Ẹ kò tíì wọlé',
480 'uploadnologintext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ [[Special:UserLogin|wọlè]] láti rùsókè faili.',
481 'uploaderror' => 'Àsìse ìrùsókè',
482 'filename' => 'Ọrúkọ faili',
483 'filedesc' => 'Àkótán',
484 'fileuploadsummary' => 'Àkótán:',
485 'uploadedfiles' => 'Àwọn faili tórùsókè',
486 'ignorewarning' => 'Fojúfo ìkìlọ̀ sì fi faili pamọ́',
487 'ignorewarnings' => 'Fojúfo ìkìlọ̀ tó wù kó jẹ́',
488 'minlength1' => 'Ó kéréjù àwọn orúkọ faili gbọdọ̀ jẹ́ lẹ́tà kan.',
489
490 # Special:ImageList
491 'imagelist_name' => 'Orúkọ',
492 'imagelist_user' => 'Oníṣe',
493
494 # Image description page
495 'filehist' => 'Ìtàn faili',
496 'filehist-current' => 'lọ́wọ́',
497 'filehist-user' => 'Oníṣe',
498 'filehist-comment' => 'Àwísọ',
499 'imagelinks' => 'Àwọn ìjápọ̀',
500 'linkstoimage' => '{{PLURAL:$1|Ojúewé yí|$1 Àwọn ojúewé yí}} jápọ̀ mọ́ àpò yí:',
501
502 # File deletion
503 'filedelete' => 'Paarẹ́ $1',
504 'filedelete-submit' => 'Paarẹ́',
505
506 # MIME search
507 'download' => 'ìrùsílẹ̀',
508
509 'withoutinterwiki' => 'Àwọn ojúewé tí kò ní ìjápọ̀ èdè',
510
511 'fewestrevisions' => 'Àwọn ojúewé pẹ̀lú àwọn àtúnyẹ̀wọ̀ tókéréjù',
512
513 # Miscellaneous special pages
514 'nbytes' => '$1 {{PLURAL:$1|byte|bytes}}',
515 'ncategories' => '{{PLURAL:$1|ẹ̀ka|àwọn ẹ̀ka}} $1',
516 'nlinks' => '{{PLURAL:$1|ìjápọ̀|àwọn ìjápọ̀}} $1',
517 'nrevisions' => '{{PLURAL:$1|àtúnyẹ̀wò|àwọn àtúnyẹ̀wò}} $1',
518 'lonelypages' => 'Àwọn ojúewé aláìlóbìí',
519 'lonelypagestext' => 'Àwọn ojúewé wọ̀nyí kò ní ìjápọ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn ojúewé míràn nínú {{SITENAME}}.',
520 'uncategorizedpages' => 'Àwọn ojúewé aláìlẹ́ka',
521 'popularpages' => 'Ojúewé tógbajúmọ̀',
522 'wantedcategories' => 'Àwọn ẹ̀ka aláìní',
523 'newpages' => 'Àwọn ojúewé tuntun',
524 'newpages-username' => 'Orúkọ oníṣe:',
525 'move' => 'Yípò',
526 'movethispage' => 'Yípò ojúewé yìí',
527
528 # Special:Log
529 'specialloguserlabel' => 'Oníṣe:',
530 'speciallogtitlelabel' => 'Àkọlé:',
531
532 # Special:AllPages
533 'allpages' => 'Gbogbo ojúewé',
534 'alphaindexline' => '$1 $2',
535 'prevpage' => 'Ojúewé sẹ́yìn ($1)',
536 'allarticles' => 'Gbogbo ojúewé',
537 'allinnamespace' => 'Gbogbo ojúewé ($1 namespace)',
538 'allnotinnamespace' => 'Gbogbo ojúewé (tí kòsí ní $1 namespace)',
539
540 # Special:Categories
541 'categories' => 'Àwọn ẹ̀ka',
542
543 # E-mail user
544 'emailfrom' => 'Láti:',
545 'emailto' => 'Sí:',
546 'emailsubject' => 'Oríọ̀rọ̀:',
547 'emailmessage' => 'Ìránṣẹ́:',
548 'emailsend' => 'Firánṣẹ́',
549
550 # Watchlist
551 'watchlist' => 'Ìmójútó mi',
552 'mywatchlist' => 'Ìmójútó mi',
553 'watchlistfor' => "(fún '''$1''')",
554 'watch' => "M'ójútó",
555 'watchthispage' => "M'ójútó ojúewé yi",
556 'unwatch' => "Já'wọ́ ìmójútó",
557 'unwatchthispage' => "Já'wọ́ ìmójútó ojúewé yi",
558 'watchlist-hide-minor' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe kékéèké',
559
560 # Displayed when you click the "watch" button and it is in the process of watching
561 'watching' => 'Ún mójútó...',
562
563 'enotif_impersonal_salutation' => 'Oníṣe {{SITENAME}}',
564 'changed' => 'tiyípadà',
565 'created' => 'tiṣèdá',
566 'enotif_subject' => '$PAGEEDITOR $CHANGEDORCREATED ojúewé $PAGETITLE lórí {{SITENAME}}',
567
568 # Delete
569 'deletedarticle' => 'A ti pa "[[$1]]" rẹ́',
570
571 # Protect
572 'protect-expiry-options' => 'wákàtí 2:2 hours,ọjọ́ 1:1 day,ọjọ́ 3:3 days,ọ̀ṣẹ̀ 1:1 week,ọ̀ṣẹ̀ 2:2 weeks,osù 1:1 month,osù 3:3 months,osù 6:6 months,ọdún 1:1 year,láìlópin:infinite', # display1:time1,display2:time2,...
573
574 # Namespace form on various pages
575 'namespace' => 'Orúkọàyè:',
576 'blanknamespace' => '(Gbangba)',
577
578 # Contributions
579 'contributions' => 'Àwọn àfikún ẹnitínṣe',
580 'mycontris' => 'Àwọn àfikún mi',
581 'contribsub2' => 'Fún $1 ($2)',
582 'uctop' => '(lókè)',
583 'month' => 'Láti osù (àti sẹ́yìn):',
584 'year' => 'Láti ọdún (àti sẹ́yìn):',
585
586 # What links here
587 'whatlinkshere' => 'Ìjápọ̀ mọ́ ojúewé yí',
588 'whatlinkshere-title' => 'Àwọn ojúewé tó jápọ̀ mọ́ "$1"',
589 'whatlinkshere-page' => 'Ojúewé:',
590 'isredirect' => 'àtúnjúwe ojúewé',
591 'whatlinkshere-links' => '← àwọn ìjápọ̀',
592
593 # Block/unblock
594 'ipbsubmit' => 'Dènà oníṣe yìí',
595 'ipboptions' => 'wákàtí 2:2 hours,ọjọ́ 1:1 day,ọjọ́ 3:3 days,ọ̀ṣẹ̀ 1:1 week,ọ̀ṣẹ̀ 2:2 weeks,osù 1:1 month,osù 3:3 months,osù 6:6 months,ọdún 1:1 year,láìlópin:infinite', # display1:time1,display2:time2,...
596 'blocklink' => 'dínà',
597 'contribslink' => 'àfikún',
598
599 # Move page
600 'move-page' => 'Yípò $1',
601 'move-page-legend' => 'Yípò ojúewé',
602 'movearticle' => 'Yípò ojúewé:',
603 'newtitle' => 'Sí àkọlé tuntun:',
604 'move-watch' => 'Mójútó ojúewé yìí',
605 'movepagebtn' => 'Yípò ojúewé',
606 'pagemovedsub' => 'Ìyípò ti já sí rere',
607 'movepage-moved' => '<big>\'\'\'"$1" ti yípò sí "$2"\'\'\'</big>', # The two titles are passed in plain text as $3 and $4 to allow additional goodies in the message.
608 'movedto' => 'tiyípò sí',
609 'movereason' => 'Ìdíẹ̀:',
610 'revertmove' => 'dápadà',
611
612 # Namespace 8 related
613 'allmessages' => 'Àwọn ìránṣẹ́ sistẹmu',
614 'allmessagesname' => 'Orúkọ',
615
616 # Tooltip help for the actions
617 'tooltip-pt-userpage' => 'Ojúewé mi',
618 'tooltip-pt-mytalk' => 'Ojúewé ọ̀rọ̀ mi',
619 'tooltip-pt-preferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn mi',
620 'tooltip-pt-watchlist' => 'Àkójọ àwọn ojúewé tí ẹ̀ ún mójútó bóyá wọ́nyí padà',
621 'tooltip-pt-mycontris' => 'Àkójọ àwọn àfikún mi',
622 'tooltip-pt-login' => 'A gbà yín níyànjú kí ẹwọlé, bótilẹ̀jẹ́pẹ́ kò pọndandan.',
623 'tooltip-pt-anonlogin' => 'A gbàyín níyànjú láti wọlé, bótilẹ̀jẹ́pé kò ṣe dandan.',
624 'tooltip-pt-logout' => 'Ìbọ́sódé',
625 'tooltip-ca-talk' => 'Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ nípa ohun inú ojúewé yìí',
626 'tooltip-ca-edit' => 'Ẹ le ṣe àtúnṣe sí ojúewé yìí.
627 Ẹ jọ̀wọ́ ẹ lo bọtini àyẹ̀wò kí ẹ tó fipamọ́.',
628 'tooltip-ca-protect' => 'Dáàbòbo ojúewé yìí',
629 'tooltip-ca-delete' => 'Pa ojúewé yìí rẹ́',
630 'tooltip-ca-move' => 'Yípò ojúewé yìí padà',
631 'tooltip-ca-watch' => "Ṣ'àfikún ojúewé yìí mọ́ ìmójútó yín",
632 'tooltip-search' => "Ṣ'àwáàrí nínú {{SITENAME}}",
633 'tooltip-p-logo' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
634 'tooltip-n-mainpage' => 'Ẹ ṣe àbẹ̀wò sí Ojúewé Àkọ́kọ́',
635 'tooltip-n-recentchanges' => 'Àkójọ àwọn àtúnṣe tuntun nínú wiki.',
636 'tooltip-t-whatlinkshere' => "Àkójọ gbogbo ojúewé wiki tó jápọ̀ s'íbí",
637 'tooltip-t-upload' => 'Ìrùsókè àwọn faili',
638 'tooltip-t-specialpages' => 'Àkójọ gbogbo àwọn ojúewé pàtàkì',
639 'tooltip-ca-nstab-category' => 'Ẹ wo ẹ́ka ojúewé',
640 'tooltip-save' => 'Àfipamọ́ àwọn àtúnṣe',
641
642 # Attribution
643 'siteuser' => '$1 oníṣe lórí {{SITENAME}}',
644 'lastmodifiedatby' => 'Igba ti a se atunse si ojuewe yi gbeyin ni $2, $1 by $3.', # $1 date, $2 time, $3 user
645
646 # Metadata
647 'metadata' => 'Metadata',
648
649 # 'all' in various places, this might be different for inflected languages
650 'watchlistall2' => 'gbogbo',
651 'namespacesall' => 'gbogbo',
652 'monthsall' => 'gbogbo',
653
654 # E-mail address confirmation
655 'confirmemail' => "Ṣè'múdájú ojúọ̀nà e-mail",
656 'confirmemail_noemail' => 'Ẹ kò ti to ojúọ̀nà e-mail tó ní bámu nínú [[Special:Preferences|ìfẹ́ràn oníṣe]] yín.',
657 'confirmemail_send' => 'Fi àmìọ̀rọ̀ ìmúdájú ránṣẹ́',
658 'confirmemail_sent' => 'E-mail ti ránṣẹ́ ìmúdájú.',
659 'confirmemail_oncreate' => 'A ti fi àmìọ̀rọ̀ ìmúdájú ránṣẹ́ sí ojúọ̀nà e-mail yín.
660 Àmìọ̀rọ̀ yìí kò pọndandan láti mú yín wọlé, sùgbọ́n ẹ gbọ́dọ̀ mu padà kí gbogbo àwọn ohun inú wiki yìí tó dúró lórí e-mail ó tó lè ṣiṣẹ́.',
661 'confirmemail_loggedin' => 'Ojúọ̀nà e-mail yín ti dájú.',
662 'confirmemail_subject' => 'Ìmúdájú ojúọ̀nà e-mail fún {{SITENAME}}',
663
664 # Special:SpecialPages
665 'specialpages' => 'Àwọn ojúewé pàtàkì',
666 'specialpages-group-maintenance' => 'Àwọn ìjábọ̀ ìtọ́jú',
667 'specialpages-group-login' => 'Ìwọlé / ìforúkọ sílẹ́',
668 'specialpages-group-pages' => 'Àkójọ àwọn ojúewé',
669 'specialpages-group-pagetools' => 'Àwọn irinṣẹ́ ojúewé',
670
671 # Special:BlankPage
672 'blankpage' => 'Ojúewé òfo',
673
674 );