Localisation updates for core messages from Betawiki (2008-10-05 10:45 CEST)
[lhc/web/wiklou.git] / languages / messages / MessagesYo.php
1 <?php
2 /** Yoruba (Yorùbá)
3 *
4 * @ingroup Language
5 * @file
6 *
7 * @author Demmy
8 */
9
10 $namespaceNames = array(
11 NS_MEDIA => 'Amóhùnmáwòrán',
12 NS_SPECIAL => 'Pàtàkì',
13 NS_TALK => 'Ọ̀rọ̀',
14 NS_USER => 'Oníṣe',
15 NS_USER_TALK => 'Ọ̀rọ̀_oníṣe',
16 NS_PROJECT_TALK => 'Ọ̀rọ̀_$1',
17 NS_IMAGE => 'Àwòrán',
18 NS_IMAGE_TALK => 'Ọ̀rọ̀_àwòrán',
19 NS_MEDIAWIKI => 'MediaWiki',
20 NS_MEDIAWIKI_TALK => 'Ọ̀rọ̀_mediaWiki',
21 NS_TEMPLATE => 'Àdàkọ',
22 NS_TEMPLATE_TALK => 'Ọ̀rọ̀_àdàkọ',
23 NS_HELP => 'Ìrànlọ́wọ́',
24 NS_HELP_TALK => 'Ọ̀rọ̀_ìrànlọ́wọ́',
25 NS_CATEGORY => 'Ẹ̀ka',
26 NS_CATEGORY_TALK => 'Ọ̀rọ̀_ẹ̀ka',
27 );
28
29 $messages = array(
30 # User preference toggles
31 'tog-underline' => 'Fàlàsí àwọn ijápọ̀:',
32 'tog-justify' => "S'àlàyé gbólóhùn ọ̀rọ̀",
33 'tog-hideminor' => "Bo àtúnse kékékèé mọ́'lẹ̀ nínú àtúnse tuntun",
34 'tog-extendwatchlist' => "Fífẹ̀ ìmójútó láti ṣ'àfihàn gbogbo àtúnṣe tó ṣẹ́lẹ̀",
35 'tog-rememberpassword' => "Sè'rántí ọ̀rọ̀ìpamí mi lórí kọmputa yi",
36 'tog-watchcreations' => "S'àfikún ojúewé tí mo dá mọ́ ìmójútó mi",
37 'tog-watchdefault' => "S'àfikún ojúewé tí mo s'àtúnse mọ́ ìmójútó mi",
38 'tog-watchmoves' => "S'àfikún ojúewé tí mo kó kúrò mọ́ ìmójútó mi",
39 'tog-watchdeletion' => "S'àfikún ojúewé tí mo parẹ́ mọ́ ìmójútó mi",
40 'tog-minordefault' => "Se àmì sí gbogbo àtúnse gẹ́gẹ́ bi kékeré lát'ìbẹ̀rẹ̀.",
41 'tog-previewontop' => "Se àyẹ̀wò kí ẹ tó s'àtúnṣe",
42 'tog-previewonfirst' => "S'àfihàn àgbéwò fún àtúnse àkọ́kọ́",
43 'tog-nocache' => "D'ènà fífi ojúewé pamọ́",
44 'tog-enotifwatchlistpages' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími tí ojúewé tí mò ún mójútó bá yípadà',
45 'tog-enotifusertalkpages' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími tí ojúewé ẹnitínse mi bá yípadà',
46 'tog-enotifminoredits' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími bákannà fún àtúnse kékékèé sí ojúewé',
47 'tog-shownumberswatching' => "S'àfihàn iye àwọn ẹnitínse tí wọn ún mójútó",
48 'tog-watchlisthideown' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe mi nínú ìmójútó',
49 'tog-watchlisthidebots' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe bot nínú ìmójútó',
50 'tog-watchlisthideminor' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe kéékèké nínú ìmójútó',
51 'tog-ccmeonemails' => 'Ìfiránṣẹ́ sími àwọn àwòkọ àwọn e-mail tí mo firánṣẹ́ sí àwọn oníṣe míràn',
52 'tog-showhiddencats' => "Ṣ'àfihàn àwọn ẹ̀ka tó pamọ́",
53
54 'underline-always' => 'Nígbà gbogbo',
55
56 # Dates
57 'sunday' => 'Ọjọ́àìkú',
58 'monday' => 'Ọjọ́ajé',
59 'tuesday' => 'Ọjọ́ìsẹ́gun',
60 'wednesday' => 'Ọjọ́rú',
61 'thursday' => 'Ọjọ́bọ̀',
62 'friday' => 'Ọjọ́ẹtì',
63 'saturday' => 'Ọjọ́àbámẹ́ta',
64 'sun' => 'Àìkú',
65 'mon' => 'Ajé',
66 'tue' => 'Ìṣẹ́gun',
67 'wed' => 'Rú',
68 'thu' => 'Bọ̀',
69 'fri' => 'Ẹtì',
70 'sat' => 'Àbámẹ́ta',
71 'january' => 'January',
72 'february' => 'February',
73 'march' => 'March',
74 'april' => 'April',
75 'may_long' => 'May',
76 'june' => 'June',
77 'july' => 'July',
78 'august' => 'August',
79 'september' => 'September',
80 'october' => 'October',
81 'november' => 'November',
82 'december' => 'December',
83 'january-gen' => 'January',
84 'february-gen' => 'February',
85 'march-gen' => 'March',
86 'april-gen' => 'April',
87 'may-gen' => 'May',
88 'june-gen' => 'June',
89 'july-gen' => 'July',
90 'august-gen' => 'August',
91 'september-gen' => 'September',
92 'october-gen' => 'October',
93 'november-gen' => 'November',
94 'december-gen' => 'December',
95 'jan' => 'Jan',
96 'feb' => 'Feb',
97 'mar' => 'Mar',
98 'apr' => 'Apr',
99 'may' => 'May',
100 'jun' => 'Jun',
101 'jul' => 'Jul',
102 'aug' => 'Aug',
103 'sep' => 'Sep',
104 'oct' => 'Oct',
105 'nov' => 'Nov',
106 'dec' => 'Dec',
107
108 # Categories related messages
109 'pagecategories' => '{{PLURAL:$1|Ẹ̀ka|Àwọn ẹ̀ka}}',
110 'category_header' => 'Àwọn ojúewé nínú ẹ̀ka "$1"',
111 'category-empty' => "''Lọ́wọ́lọ́wọ́ ẹ̀ka yìí kò ní ojúewé tàbí amóhùnmáwòrán kankan.''",
112 'hidden-categories' => '{{PLURAL:$1|Ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀|Áwọn ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀}}',
113 'hidden-category-category' => 'Àwọn ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀', # Name of the category where hidden categories will be listed
114 'listingcontinuesabbrev' => 'tẹ̀síwájú',
115
116 'about' => 'Nípa',
117 'newwindow' => '(yíò sí nínú fèrèsè tuntun)',
118 'cancel' => "Fa'gilé",
119 'qbfind' => 'Wá rí',
120 'qbedit' => 'Àtúnṣe',
121 'qbpageoptions' => 'Ojúewé yi',
122 'qbmyoptions' => 'Àwọn ojúewé mi',
123 'qbspecialpages' => 'Àwọn ojúewé pàtàkì',
124 'moredotdotdot' => 'Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́...',
125 'mypage' => 'Ojúewé mi',
126 'mytalk' => 'Ọ̀rọ̀ mi',
127 'anontalk' => 'Ọ̀rọ̀ fún IP yí',
128 'navigation' => 'Atọ́ka',
129 'and' => 'àti',
130
131 'errorpagetitle' => 'Àsìse',
132 'returnto' => 'Padà sí $1.',
133 'tagline' => "Lát'ọwọ́ {{SITENAME}}",
134 'help' => 'Ìrànlọ́wọ́',
135 'search' => 'Ṣe àwáàrí',
136 'searchbutton' => 'Ṣe àwáàrí',
137 'go' => 'Ó yá',
138 'searcharticle' => 'Ó yá',
139 'history' => 'Ìtàn ojúewé',
140 'history_short' => '
141 Ìtàn',
142 'updatedmarker' => 'jẹ́ títúnṣe lẹ́yìn àbẹ̀wò mi',
143 'printableversion' => 'Títẹ̀ sí ìwé',
144 'permalink' => 'Ìjápọ̀ tíkòníyípadà',
145 'print' => 'Tẹ̀síìwé',
146 'edit' => 'Àtúnṣe',
147 'create' => "Ṣè'dá",
148 'editthispage' => "S'àtúnṣe ojúewé yi",
149 'create-this-page' => "Ṣè'dá ojúewé yìí",
150 'delete' => 'Paarẹ́',
151 'deletethispage' => 'Pa ojúewé yi rẹ́',
152 'protect' => 'Dábòbò',
153 'protectthispage' => 'Dá àbò bo ojúewé yìí',
154 'unprotect' => 'Mú àbò kúrò',
155 'unprotectthispage' => 'Mú àbò kúrò lórí ojúewé yìí',
156 'newpage' => 'Ojúewé tuntun',
157 'talkpage' => 'Kábárawasọ̀rọ̀ nípa ojúewé yi',
158 'talkpagelinktext' => 'Kábárawasọ̀rọ̀',
159 'specialpage' => 'Ojúewé Pàtàkì',
160 'personaltools' => 'Àwọn irinṣẹ́ àdáni',
161 'postcomment' => 'Ṣe àwísọ',
162 'talk' => 'Ìfọ̀rọ̀wérọ̀',
163 'views' => 'Àwọn ìwò',
164 'toolbox' => 'Àpótí irinṣẹ',
165 'userpage' => 'Wo ojúewé oníṣe',
166 'projectpage' => 'Wo ojúewé iṣẹ́ọwọ́',
167 'imagepage' => 'Wo ojúewé amóhùnmáwòrán',
168 'mediawikipage' => 'Wo ojúewé ìránṣẹ́',
169 'templatepage' => 'Wo ojúewé àdàkọ',
170 'viewhelppage' => 'Wo ojúewé ìrànlọ́wọ́',
171 'categorypage' => 'Wo ojúewé ẹ̀ka',
172 'viewtalkpage' => 'Wo ìfọ̀rọ̀wérọ̀',
173 'otherlanguages' => 'Àwọn èdè míràn',
174 'redirectedfrom' => '(Àtúnjúwe láti $1)',
175 'redirectpagesub' => 'Ojúewé àtúnjúwe',
176 'lastmodifiedat' => 'Ọjọ́ tí a ṣe àtunṣe ojúewé yi gbẹ̀yìn ni $2, $1.', # $1 date, $2 time
177 'viewcount' => 'A ti wo ojúewé yi ni {{PLURAL:$1|ẹ̀kan péré|iye ìgbà $1}}.',
178 'protectedpage' => 'Ojúewé aláàbò',
179 'jumptonavigation' => 'atọ́ka',
180 'jumptosearch' => "
181 ṣ'àwáàrí",
182
183 # All link text and link target definitions of links into project namespace that get used by other message strings, with the exception of user group pages (see grouppage) and the disambiguation template definition (see disambiguations).
184 'aboutsite' => 'Nípa {{SITENAME}}',
185 'aboutpage' => 'Project:Nípa',
186 'copyright' => 'Gbogbo ohun inú ibí yi wà lábẹ́ $1.',
187 'copyrightpagename' => '{{SITENAME}} ẹ̀tọ́àwòkọ',
188 'copyrightpage' => '{{ns:project}}:Ẹ̀tọ́àwòko',
189 'currentevents' => 'Ìròhìn nísinsìnyí',
190 'currentevents-url' => 'Project:Ìròhìn nísinsìnyí',
191 'disclaimers' => 'Ikìlọ̀',
192 'disclaimerpage' => 'Project:Ìkìlọ̀ gbogbo',
193 'edithelp' => "Ìrànlọ́wọ́ láti s'àtúnṣe",
194 'edithelppage' => 'Help:Àtúnṣe',
195 'mainpage' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
196 'mainpage-description' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
197 'portal' => 'Èbúté àwùjọ',
198 'portal-url' => 'Project:Èbúté Àwùjọ',
199 'privacy' => 'Ètò àbò',
200 'privacypage' => 'Project:Ètò àbò',
201
202 'badaccess-group0' => "A kò gbàyín l'áyè l'áti ṣe ohun tí ẹ bèrè fún.",
203
204 'ok' => 'OK',
205 'youhavenewmessages' => 'Ẹ ní $1 ($2).',
206 'newmessageslink' => 'ìfọ̀rọ̀ránsẹ́ tuntun',
207 'newmessagesdifflink' => 'àtúnṣe ìgbẹ̀yìn',
208 'youhavenewmessagesmulti' => 'Ẹ ní ìfọ̀rọ̀ránsẹ́ tuntun ni $1',
209 'editsection' => "s'àtúnṣe",
210 'editold' => "s'àtúnṣe",
211 'viewsourceold' => 'wo àmìọ̀rọ̀',
212 'editsectionhint' => 'Abala àtúnṣe: $1',
213 'showtoc' => 'fihàn',
214 'hidetoc' => 'bòmọ́lẹ̀',
215 'thisisdeleted' => 'Wo tàbí múpadà $1?',
216 'viewdeleted' => 'Wo $1?',
217 'restorelink' => '{{PLURAL:$1|àtúnṣe tóparẹ́ kan|àtúnṣe tóparẹ́ $1}}',
218 'site-rss-feed' => '$1 RSS Feed',
219 'site-atom-feed' => '$1 Atom Feed',
220 'page-rss-feed' => '"$1" RSS Feed',
221
222 # Short words for each namespace, by default used in the namespace tab in monobook
223 'nstab-main' => 'Àyọkà',
224 'nstab-user' => 'Ojúewé oníṣe',
225 'nstab-media' => 'Ojúewé amóhùnmáwòrán',
226 'nstab-special' => 'Pàtàkì',
227 'nstab-project' => 'Ojúewé iṣẹ́ọwọ́',
228 'nstab-image' => 'Faili',
229 'nstab-mediawiki' => 'Ìfọ̀rọ̀ránsẹ',
230 'nstab-template' => 'Àdàkọ',
231 'nstab-help' => 'Ojúewé ìrànlọ́wọ́',
232 'nstab-category' => 'Ẹ̀ka',
233
234 # Main script and global functions
235 'nosuchaction' => 'Kò sí irú ìgbéṣe báun',
236 'nosuchactiontext' => 'Ìgbéṣe tí URL yìí tọ́kasí kò ní ìdámọ̀ lórí wiki yìí',
237 'nosuchspecialpage' => 'Kò sí irú ojúewé pàtàkì báun',
238 'nospecialpagetext' => "<big>'''Ẹ tọrọ ojúewé pàtàkì tólòdì.'''</big>
239
240 Àkójọ àwọn ojúewé pàtàkì tóbámu wà ní [[Special:SpecialPages|{{int:specialpages}}]].",
241
242 # General errors
243 'error' => 'Àsìṣe',
244 'missingarticle-diff' => '(Ìyàtọ̀: $1, $2)',
245 'filecopyerror' => 'Àwòkọ faili "$1" sí "$2" kò ṣe é ṣe.',
246 'filerenameerror' => 'Àtúnsọlórúkọ faili "$1" sí "$2" kò ṣe é ṣe.',
247 'filedeleteerror' => 'Ìparẹ́ faili "$1" kò ṣe é ṣe.',
248 'directorycreateerror' => 'Ìwé-ìjúwe "$1" kò ṣe é ṣe.',
249 'filenotfound' => 'Kò le é ṣe àwáàrí faili "$1".',
250 'badtitle' => 'Àkọ́lé burúkú',
251 'viewsource' => 'Àfihàn ọ̀rọ̀àmì',
252 'viewsourcefor' => 'fún $1',
253 'protectedpagetext' => 'A ti se àtìpa ojúewé yi. Ẹ kò le se àtúnṣe.',
254 'viewsourcetext' => 'Ẹ lè wo ati ẹ lè se àwòkọ ọ̀rọ̀àmì ojúewé yi:',
255 'ns-specialprotected' => 'Àtúnṣe kò ṣe é ṣe sí àwọn ojúewé pàtàkì.',
256 'titleprotected' => "This title has been protected from creation by [[User:$1|$1]]. The reason given is ''$2''.",
257
258 # Login and logout pages
259 'logouttitle' => 'Ibọsóde oníṣe',
260 'logouttext' => "<strong>Ẹ ti bọ́sọ́de.</strong>
261
262 Ẹ le tẹ̀síwájú sí ní lo {{SITENAME}} láìmorúkọ yín, tàbí kí ẹ [[Special:UserLogin|padà wọlé]] bí ẹnikanan tàbí ẹlòmíràn.
263 Àkíyèsí wípé àwọn ojúewé kan le hàn b'ígbà tójẹ́pé ẹ sì wọlé títí tí ẹ ó fi jọ̀wọ́ àdìmú (cache) browser yín.",
264 'welcomecreation' => "== Ẹ kú àbọ̀, $1! ==
265
266 A ti fi orúkọ yín s'ílẹ̀. Ẹ mọ́ gbàgbé l'áti s'àtúnṣe àwọn ìfẹ́ràn {{SITENAME}} yín.",
267 'loginpagetitle' => 'Ìwọlé oníṣe',
268 'yourname' => 'Orúkọ oníṣe (username):',
269 'yourpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́:',
270 'yourpasswordagain' => 'Tẹkíkọ ọ̀rọ̀ìpamọ́ lẹ́ẹ̀kansí:',
271 'remembermypassword' => "Sè'rántí ọ̀rọ̀ìpamí mi lórí kọmputa yi (cookies)",
272 'login' => 'Ìwọlé',
273 'nav-login-createaccount' => 'Ìwọlé / Ìforúkọ sílẹ̀',
274 'loginprompt' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ jọ̀wọ́ cookies láti wọlé sí {{SITENAME}}.',
275 'userlogin' => 'Ìwọlé / ìforúkọ sílẹ̀',
276 'logout' => 'Ìbọ́sóde',
277 'userlogout' => 'Ìbọ́sóde',
278 'notloggedin' => "Ẹ kò tí w'ọlé",
279 'nologin' => 'Ṣé ẹ fẹ́ wọlé? $1.',
280 'nologinlink' => 'Ẹ fi orúkọ sílẹ̀',
281 'createaccount' => 'Ẹ fi orúkọ sílẹ̀',
282 'gotaccount' => 'Ṣé ẹ ti ní àpamọ́ tẹ́lẹ̀? $1.',
283 'gotaccountlink' => "Ẹ w'ọlé",
284 'createaccountmail' => 'pẹ̀lú e-mail',
285 'badretype' => 'Àwọn ọ̀rọ̀ìpamọ́ tí ẹ kọ kò jọ ra wọn.',
286 'youremail' => 'E-mail:',
287 'username' => 'Orúkọ oníṣe:',
288 'uid' => 'Nọmba ìdámọ̀ fún ẹnitínṣe:',
289 'yourrealname' => 'Orúkọ ganangan:',
290 'yourlanguage' => 'Èdè:',
291 'yournick' => 'Ìtọwọ́bọ̀:',
292 'badsiglength' => 'Ìtọwọ́bọ̀ yín ti gùnjù.
293 Kò gbodọ̀ ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà|àwọn àmìlẹ́tà}} $1 lọ.',
294 'email' => 'E-mail',
295 'loginerror' => 'Àsìṣe ìwọlé',
296 'prefs-help-email-required' => 'E-mail ṣe dandan.',
297 'noname' => 'Ẹ kò tọ́kasí orúkọ oníṣe tó ní ìbámu.',
298 'loginsuccesstitle' => 'Ìwọlé ti yọrí sí rere',
299 'loginsuccess' => "'''Ẹ ti wọlé sínú {{SITENAME}} gẹ́gẹ́ bi \"\$1\".'''",
300 'nosuchuser' => 'Kò sí oníṣe kankan pẹ̀lú orúkọ "$1".
301 Ẹ yẹ lẹ́tà yín wò, tàbí [[Special:Userlogin/signup|kí ẹ s\'èdá àpamọ́ tuntun]].',
302 'nouserspecified' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ tọ́kasí orúkọ oníṣe kan.',
303 'wrongpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tí ẹ kìbọ́ kòtọ́.
304 Ẹ jọ̀wọ́ ẹ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kansí.',
305 'passwordtooshort' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín jẹ́ aláìtọ́ tàbí ó kúrú ju bóṣe yẹ lọ.
306 Kò gbọ́dọ̀ dín ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà kan|àmìlẹ́tà $1}} lọ, kí ó sì yàtọ̀ sí oríkọoníṣe yín.',
307 'mailmypassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun sí e-mail',
308 'noemail' => 'Kò sí àkọsílẹ̀ ojúọ̀nà e-mail fún oníṣe "$1".',
309 'emailauthenticated' => 'Ojúọ̀nà e-mail yín fidájú ní ago $3 ọjọ́ $2.',
310 'emailconfirmlink' => 'Ẹ ṣe ìmúdájú ojúọ̀nà e-mail yín',
311 'accountcreated' => 'Ẹ ti fi orúkọ sílẹ̀',
312 'accountcreatedtext' => "A ti ṣ'èdá àpamọ́ oniṣe fún $1.",
313 'createaccount-title' => 'Ìforúkọ sílẹ̀ fún {{SITENAME}}',
314 'loginlanguagelabel' => 'Èdè: $1',
315
316 # Password reset dialog
317 'resetpass' => 'Àtúntò ọ̀rọ̀ìpamọ́ àpamọ́',
318 'resetpass_header' => 'Àtúntò ọ̀rọ̀ìpamọ́',
319 'resetpass_success' => 'Ìyípadà ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín ti já sí rere! Ẹ̀ ún wọlé lọ́wọ́...',
320
321 # Edit page toolbar
322 'bold_sample' => 'Ìkọ kedere',
323 'bold_tip' => 'Ìkọ kedere',
324 'italic_sample' => 'Ìkọ italiki',
325 'italic_tip' => 'Ìkọ italiki',
326 'link_sample' => 'Àkọlé ìjápọ̀',
327 'link_tip' => "Ìjápọ̀ s'ínú",
328 'extlink_sample' => 'http://www.example.com àkọlé ìjápọ̀',
329 'extlink_tip' => "Ìjápọ̀ s'íta (ẹ mọ́ gbàgbé http:// prefix)",
330 'headline_sample' => 'Ìkọ àkọlé',
331 'headline_tip' => 'Àkọlé onípele 2',
332 'math_sample' => "Ẹ fi àgbékalẹ̀ s'íhín",
333 'math_tip' => 'Àgbékalẹ̀ ìsirò (LaTeX)',
334 'nowiki_sample' => "Ẹ fi ìkọ tí kò létò s'íhín",
335 'nowiki_tip' => 'Ẹ fojú fo étò wiki',
336 'image_tip' => 'Faili tí a kìbọ̀',
337 'media_tip' => 'Ìjápọ̀ faili',
338 'sig_tip' => 'Ìtọwọ́bọ̀ yín pẹ̀lú àmì-àsìkò',
339 'hr_tip' => 'Ìlà gbọlọjọ (ẹ lọ̀ọ́ pẹ̀lú àkíyèsì)',
340
341 # Edit pages
342 'summary' => 'Àkótán',
343 'minoredit' => 'Àtúnṣe kékeré nìyí',
344 'watchthis' => "M'ójútó ojúewé yìí",
345 'savearticle' => 'Ẹ fi pamọ́',
346 'preview' => 'Àyẹ̀wò',
347 'showpreview' => 'Àyẹ̀wò',
348 'showdiff' => 'Àfihàn àwọn àyípadà',
349 'anoneditwarning' => "'''Ìkìlọ̀:''' Ẹ ò tíì wọlé.
350 Á ṣe àkọsílẹ̀ ojúọ̀nà IP yín ninu ìwé àtúnṣe ojúewé yìí.",
351 'blockedtitle' => 'Ìdènà sí oníṣe',
352 'whitelistedittitle' => "Ìwọlé ṣe dandan láti ṣ'àtúnṣe",
353 'whitelistedittext' => "Ẹ gbọ́dọ̀ $1 láti ṣ'àtúnṣe àwọn ojúewé.",
354 'confirmedittitle' => "Ìmúdájú E-mail ṣe dandan láti ṣ'àtúnṣe",
355 'nosuchsectiontitle' => 'Kò sí irú abala báun',
356 'loginreqtitle' => "Ẹ gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ w'ọlé ná",
357 'loginreqlink' => 'ìwọlé',
358 'loginreqpagetext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ $1 láti wo àwọn ojúewé míràn.',
359 'accmailtitle' => 'Ti fi ọ̀rọ̀ìpamọ́ ránṣẹ́.',
360 'accmailtext' => 'A ti fi ọ̀rọ̀ìpamọ́ fún "$1" ránṣẹ́ sí $2.',
361 'newarticle' => '(Tuntun)',
362 'newarticletext' => "Ẹ ti tẹ̀lé ìjápọ̀ mọ́ ojúewé tí kò sí.
363 Láti dá ojúewé yí ẹ bẹ̀rẹ̀ síní tẹ́kọ sí inú àpótí ìsàlẹ̀ yí (ẹ wo [[{{MediaWiki:Helppage}}|ojúewé ìrànlọ́wọ́ ]] fun ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ).
364 T'óbá sepé àsìse ló gbé yin dé bi, ẹ kọn bọ́tìnì ìpadàsẹ́yìn.",
365 'noarticletext' => "Lọ́wọ́lọ́wọ́ kò sí ìkọ nínú ojúewé yìí, ẹ le [[Special:Search/{{PAGENAME}}|s'àwáarí fún àkọlé ojúewé yìí]] nínú àwọn ojúewé mìíràn tàbí [{{fullurl:{{FULLPAGENAME}}|action=edit}} kí ẹ ṣ'àtúnṣe ojúewé òún].",
366 'note' => '<strong>Àkíyèsí:</strong>',
367 'previewnote' => '<strong>Àyẹ̀wò kan ni èyí;
368 àwọn àtúnṣe kò tíì pamọ́!</strong>',
369 'session_fail_preview' => '<strong>Àforíjìn! A kò le gbésẹ̀ àtúnṣe yín nítorí ìpòfo data ìsinsìyí.
370 Ẹ jọ̀wọ́ ẹ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan si.
371 Tí kò bá sì tún ṣiṣẹ́, ẹ gbìyànjú láti [[Special:UserLogout|bọ̀sòde]] kí ẹ sì padá wọlé.</strong>',
372 'editing' => 'Àtúnṣe sí $1',
373 'editingsection' => 'Àtúnṣe sí $1 (abala)',
374 'yourdiff' => 'Àwọn ìyàtọ̀',
375 'copyrightwarning' => 'Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kíyèsi wípé gbogbo àwọn àfikún sí {{SITENAME}} jẹ́ bẹ̀ lábẹ́ $2 (Ẹ wo $1 fún ẹkunrẹrẹ).
376 Tí ẹ kò bá fẹ́ kí ìkọọ́lẹ̀ yín ó jẹ́ títúnṣe tàbí kì ó jẹ́ pípìn kiri lọ́ná tí kò wù yín, ẹ mọ́ mù wá síbí.<br />
377 Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín, tàbí ẹ wòókọ láti agbègbè ìgboro tàbí irú ìtìlẹ́yín ọ̀fẹ́ bíi bẹ́ẹ̀.
378 <strong>Ẹ MỌ́ MÚ IṢẸ́ TÓ NÍ Ẹ̀TỌ́ÀWÒKỌ SÍLẸ̀ LÁÌ GBÀṢẸ!</strong>',
379 'templatesused' => 'Àwọn àdàkọ tí a lò lórí ojúewé yìí:',
380 'templatesusedpreview' => 'Àwọn àdàkọ tí a lò nìnú àgbéyẹ́wò yìí:',
381 'template-protected' => '(aláàbò)',
382 'template-semiprotected' => '(aláàbò díẹ̀)',
383 'nocreatetext' => "{{SITENAME}} ti pààlà ààyè láti ṣ'èdá ojúewé tuntun.
384 Ẹ le padà sẹ́yìn kí ẹ ṣ'àtúnṣe ojúewé tó wà, tàbí [[Special:UserLogin|kí ẹ wọlé tàbí kí ẹ ṣ'èdá àpamọ́]].",
385 'recreate-deleted-warn' => "'''Ìkìlọ̀: Ẹ̀ ún ṣ'èdá ojúewé tí a ti parẹ́ tẹ́lẹ̀.'''
386
387 Ẹ gbọ́dọ̀ gberò bóyá ó bójúmu láti tẹ̀síwájú pẹ̀lú àtúnṣe ojúewé yìí.
388 Àkọsílẹ̀ ìparẹ́ nìyí fún ìrọ̀rùn:",
389
390 # Account creation failure
391 'cantcreateaccounttitle' => 'Ìforúkọsílẹ̀ kò se é se',
392
393 # History pages
394 'viewpagelogs' => 'Ẹ wo àkọsílẹ̀ fún ojúewé yìí',
395 'currentrev' => 'Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí',
396 'revisionasof' => 'Àtúnyẹ̀wò ní $1',
397 'revision-info' => "Àtúnyẹ̀wò ní $1 l'átọwọ́ $2",
398 'previousrevision' => '← Àtúnyẹ̀wò tópẹ́ju',
399 'nextrevision' => 'Àtúnyẹ̀wò tótuntunju →',
400 'currentrevisionlink' => 'Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí',
401 'cur' => 'lọ́wọ́',
402 'next' => 'tókàn',
403 'last' => 'tẹ́lẹ̀',
404 'page_first' => 'àkọ́kọ́',
405 'page_last' => 'tógbẹ̀yìn',
406 'deletedrev' => '[tiparẹ́]',
407 'historyempty' => '(òfo)',
408
409 # Revision feed
410 'history-feed-title' => 'Ìtàn àtúnyẹ̀wò',
411 'history-feed-description' => 'Ìtàn àtúnyẹ̀wò fún ojúewé yìí ní orí wiki',
412 'history-feed-item-nocomment' => '$1 $2', # user at time
413
414 # Revision deletion
415 'rev-delundel' => 'fihàn/bòmọ́lẹ̀',
416 'pagehist' => 'Ìtàn ojúewé',
417 'deletedhist' => 'Ìtàn ìparẹ́',
418 'revdelete-summary' => 'àkótán àtúnṣe',
419 'revdelete-uname' => 'orúkọ oníṣe',
420
421 # Diffs
422 'history-title' => 'Ìtàn àtúnyẹ̀wò fún "$1"',
423 'difference' => '(Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ́wò)',
424 'lineno' => 'Ìlà $1:',
425 'compareselectedversions' => 'Ìfiwéra àwọn àtúnṣe ìṣàyàn',
426 'editundo' => 'dápadà',
427 'diff-movedto' => 'tiyípò sí $1',
428
429 # Search results
430 'searchresults' => 'Àwọn èsì àwáàrí',
431 'searchresults-title' => 'Àwọn èsì àwáàrí fún $1',
432 'searchsubtitle' => 'Ẹ ṣ\'àwáàrí fun \'\'\'[[:$1]]\'\'\' ([[Special:Prefixindex/$1|gbogbo ojúewé tó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lu "$1"]] | [[Special:WhatLinksHere/$1|gbogbo ojúewé tó jápọ̀ mọ́ "$1"]])',
433 'searchsubtitleinvalid' => "Ẹ ṣ'àwáàrí fun '''$1'''",
434 'noexactmatch' => "'''Kò sí ojúewé pẹ̀lú àkọlé \"\$1\".'''
435 Ẹ le [[:\$1|ṣ'èdá ojúewé yìí]].",
436 'noexactmatch-nocreate' => "'''Kò sí ojúewé pẹ̀lú àkọlé \"\$1\".'''",
437 'prevn' => 'titẹ́lẹ̀ $1',
438 'nextn' => 'tókàn $1',
439 'viewprevnext' => 'Ẹ wo ($1) ($2) ($3)',
440 'search-relatedarticle' => 'Tóbáramu',
441 'searchrelated' => 'tóbáramu',
442 'searchall' => 'gbogbo',
443 'powersearch' => 'Ṣe àwáàrí',
444 'powersearch-legend' => 'Àwáàrí gíga',
445 'powersearch-ns' => 'Àwáàrí nínú orúkọàyè:',
446 'powersearch-redir' => 'Àkójọ àwọn àtúnjúwe',
447 'powersearch-field' => 'Àwáàrí fún',
448
449 # Preferences page
450 'preferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn',
451 'mypreferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn mi',
452 'prefs-edits' => 'Iye àwọn àtúnṣe:',
453 'prefsnologin' => 'Ẹ kò tíì wọlé',
454 'prefsnologintext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ <span class="plainlinks">[{{fullurl:Special:Userlogin|returnto=$1}} wọlé]</span> láti to àwọn ìfẹ́ràn oníṣe.',
455 'changepassword' => 'Ìyípadà ọ̀rọ̀ìpamọ́',
456 'skin' => 'Skin (Àwọ̀)',
457 'dateformat' => 'Ìṣájúètò ọjọ́',
458 'datedefault' => 'Kò sí ìfẹ́ràn',
459 'datetime' => 'Ọjọ́ àti àkókò',
460 'prefs-personal' => 'Ọ̀rọ̀ nípa oníṣe',
461 'prefs-rc' => 'Àwọn àtúnṣe tuntun',
462 'prefs-watchlist' => 'Ìmójútó',
463 'prefs-watchlist-days' => 'Ọjọ́ láti fihàn nínú ìmójútó:',
464 'saveprefs' => 'Ìfipamọ́',
465 'resetprefs' => 'Palẹ̀mọ́ àwọn àtúnṣe tí kò sì ní ìpamọ́',
466 'oldpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ titẹ́lẹ̀:',
467 'newpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun:',
468 'searchresultshead' => 'Àwáàrí',
469 'savedprefs' => 'Àwọn ìfẹ́ràn yín ti wà nípamọ́.',
470 'prefs-searchoptions' => 'Àwọn ìyàn àwáàrí',
471 'prefs-namespaces' => 'Àwọn orúkọàyè',
472 'files' => 'Àwọn faili',
473
474 # Groups
475 'group' => 'Àkójọpọ̀:',
476 'group-autoconfirmed' => 'Àwọn oníṣe ìmúdájú fúnrawọn',
477 'group-sysop' => 'Àwọn alámùójútó',
478
479 'grouppage-user' => '{{ns:project}}:Àwọn oníṣe',
480 'grouppage-autoconfirmed' => '{{ns:project}}:Àwọn oníṣe ìmúdájú fùnrawọn',
481 'grouppage-bot' => '{{ns:project}}:Àwọn Bot',
482 'grouppage-sysop' => '{{ns:project}}:Àwọn alámùójútó',
483
484 # Recent changes
485 'recentchanges' => 'Àwọn àtúnṣe tuntun',
486 'rcnote' => "Lábẹ́ yìí ni {{PLURAL:$1|àtúnṣe '''kan'''|àwọn àtúnṣe '''$1'''}} tó kẹ̀yìn ní ọjọ́ '''$2''' sẹ́yìn, ní ago $5, ọjọ́ $4.",
487 'rclistfrom' => 'Àfihàn àwọn àtúnṣe tuntun nípa bíbẹ̀rẹ̀ láti $1',
488 'rcshowhideminor' => '$1 àwọn àtúnṣe kékéèké',
489 'rcshowhidebots' => '$1 àwọn bot',
490 'rcshowhideliu' => '$1 àwọn oníṣe tótiwọlé',
491 'rcshowhideanons' => '$1 àwọn oníṣe aláìlórúkọ',
492 'rcshowhidemine' => '$1 àwọn àtúnṣe mi',
493 'rclinks' => "Ṣ'àfihàn àtúnṣe $1 tó kẹ̀yìn ní ọjọ́ $2 sẹ́yìn<br />$3",
494 'diff' => 'ìyàtọ̀',
495 'hist' => 'ìtàn',
496 'hide' => 'Ìbòmọ́lẹ̀',
497 'show' => 'Àfihàn',
498 'minoreditletter' => 'k',
499 'newpageletter' => 'T',
500 'boteditletter' => 'b',
501 'rc_categories_any' => 'Èyíkéyìí',
502 'newsectionsummary' => '/* $1 */ abala tuntun',
503
504 # Recent changes linked
505 'recentchangeslinked' => 'Àtúnṣe tó báramu',
506 'recentchangeslinked-title' => 'Àtúnṣe tó báramu mọ́ "$1"',
507 'recentchangeslinked-summary' => "Àkójọ àwọn àtúnṣe tí a sẹ̀sẹ̀ ṣe sí àwọn ojúewé tó jápọ̀ wá láti ojúewé pàtó kan (tàbí sí ìkan nìnú ẹ̀ka pàtó kan).
508 Àwọn ojúewé inú [[Special:Watchlist|ìmójútó yín]] jẹ́ '''kedere'''.",
509 'recentchangeslinked-page' => 'Orúkọ ojúewé:',
510
511 # Upload
512 'upload' => 'Ìrùsókè faili',
513 'uploadbtn' => 'Ìrùsókè faili',
514 'reupload' => 'Àtún-rùsókè',
515 'uploadnologin' => 'Ẹ kò tíì wọlé',
516 'uploadnologintext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ [[Special:UserLogin|wọlè]] láti rùsókè faili.',
517 'uploaderror' => 'Àsìse ìrùsókè',
518 'uploadlogpage' => 'Àkọsílẹ̀ ìrùsókè',
519 'filename' => 'Ọrúkọ faili',
520 'filedesc' => 'Àkótán',
521 'fileuploadsummary' => 'Àkótán:',
522 'uploadedfiles' => 'Àwọn faili tórùsókè',
523 'ignorewarning' => 'Fojúfo ìkìlọ̀ sì fi faili pamọ́',
524 'ignorewarnings' => 'Fojúfo ìkìlọ̀ tó wù kó jẹ́',
525 'minlength1' => 'Ó kéréjù àwọn orúkọ faili gbọdọ̀ jẹ́ lẹ́tà kan.',
526 'uploadedimage' => 'ti ru "[[$1]]" s\'ókè',
527
528 # Special:ImageList
529 'imagelist_name' => 'Orúkọ',
530 'imagelist_user' => 'Oníṣe',
531
532 # Image description page
533 'filehist' => 'Ìtàn faili',
534 'filehist-help' => 'Ẹ kan ọjọ́/àsìkò kan láti wo faili òún bó ṣe hàn ní ìgbà na.',
535 'filehist-current' => 'lọ́wọ́',
536 'filehist-datetime' => 'Ọjọ́/Àsìkò',
537 'filehist-user' => 'Oníṣe',
538 'filehist-filesize' => 'Ìtóbi faili',
539 'filehist-comment' => 'Àwísọ',
540 'imagelinks' => 'Àwọn ìjápọ̀',
541 'linkstoimage' => '{{PLURAL:$1|Ojúewé yí|$1 Àwọn ojúewé yí}} jápọ̀ mọ́ àpò yí:',
542 'sharedupload' => 'Faili yìí jẹ́ ìrùsókè pínpín pẹ̀lú àwọn iṣẹ́owọ́ mìíràn tí wọ́n n lòó.',
543
544 # File deletion
545 'filedelete' => 'Paarẹ́ $1',
546 'filedelete-submit' => 'Paarẹ́',
547
548 # MIME search
549 'download' => 'ìrùsílẹ̀',
550
551 # Statistics
552 'statistics' => 'Àwọn statistiki',
553
554 'withoutinterwiki' => 'Àwọn ojúewé tí kò ní ìjápọ̀ èdè',
555
556 'fewestrevisions' => 'Àwọn ojúewé pẹ̀lú àwọn àtúnyẹ̀wọ̀ tókéréjù',
557
558 # Miscellaneous special pages
559 'nbytes' => '$1 {{PLURAL:$1|byte|bytes}}',
560 'ncategories' => '{{PLURAL:$1|ẹ̀ka|àwọn ẹ̀ka}} $1',
561 'nlinks' => '{{PLURAL:$1|ìjápọ̀|àwọn ìjápọ̀}} $1',
562 'nrevisions' => '{{PLURAL:$1|àtúnyẹ̀wò|àwọn àtúnyẹ̀wò}} $1',
563 'lonelypages' => 'Àwọn ojúewé aláìlóbìí',
564 'lonelypagestext' => 'Àwọn ojúewé wọ̀nyí kò ní ìjápọ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn ojúewé míràn nínú {{SITENAME}}.',
565 'uncategorizedpages' => 'Àwọn ojúewé aláìlẹ́ka',
566 'popularpages' => 'Ojúewé tógbajúmọ̀',
567 'wantedcategories' => 'Àwọn ẹ̀ka aláìní',
568 'protectedpages' => 'Àwọn ojúewé aláàbò',
569 'listusers' => 'Àkójọ àwọn oníṣe',
570 'newpages' => 'Àwọn ojúewé tuntun',
571 'newpages-username' => 'Orúkọ oníṣe:',
572 'move' => 'Yípò',
573 'movethispage' => 'Yípò ojúewé yìí',
574
575 # Special:Log
576 'specialloguserlabel' => 'Oníṣe:',
577 'speciallogtitlelabel' => 'Àkọlé:',
578 'log' => 'Àwọn àkọsílẹ̀',
579
580 # Special:AllPages
581 'allpages' => 'Gbogbo ojúewé',
582 'alphaindexline' => '$1 $2',
583 'prevpage' => 'Ojúewé sẹ́yìn ($1)',
584 'allpagesfrom' => 'Àgbéhàn ojúewé tó bẹ̀rẹ̀ láti:',
585 'allarticles' => 'Gbogbo ojúewé',
586 'allinnamespace' => 'Gbogbo ojúewé ($1 namespace)',
587 'allnotinnamespace' => 'Gbogbo ojúewé (tí kòsí ní $1 namespace)',
588
589 # Special:Categories
590 'categories' => 'Àwọn ẹ̀ka',
591
592 # E-mail user
593 'emailuser' => 'Ẹ fi e-mail ránṣẹ́ sí oníṣe yìí',
594 'emailfrom' => 'Láti:',
595 'emailto' => 'Sí:',
596 'emailsubject' => 'Oríọ̀rọ̀:',
597 'emailmessage' => 'Ìránṣẹ́:',
598 'emailsend' => 'Firánṣẹ́',
599
600 # Watchlist
601 'watchlist' => 'Ìmójútó mi',
602 'mywatchlist' => 'Ìmójútó mi',
603 'watchlistfor' => "(fún '''$1''')",
604 'watch' => "M'ójútó",
605 'watchthispage' => "M'ójútó ojúewé yi",
606 'unwatch' => "Já'wọ́ ìmójútó",
607 'unwatchthispage' => "Já'wọ́ ìmójútó ojúewé yi",
608 'wlshowlast' => 'Áfihàn wákàtí $1 sẹ́yìn ọjọ́ $2 sẹ́yìn $3',
609 'watchlist-hide-bots' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe bot',
610 'watchlist-hide-own' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe mi',
611 'watchlist-hide-minor' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe kékéèké',
612
613 # Displayed when you click the "watch" button and it is in the process of watching
614 'watching' => 'Ún mójútó...',
615
616 'enotif_impersonal_salutation' => 'Oníṣe {{SITENAME}}',
617 'changed' => 'tiyípadà',
618 'created' => 'tiṣèdá',
619 'enotif_subject' => '$PAGEEDITOR $CHANGEDORCREATED ojúewé $PAGETITLE lórí {{SITENAME}}',
620
621 # Delete
622 'historywarning' => 'Ìkìlọ̀: Ojúewé tí ẹ fẹ́ parẹ́ ní ìtàn:',
623 'actioncomplete' => 'Ìmúṣe ti parí',
624 'deletedarticle' => 'A ti pa "[[$1]]" rẹ́',
625
626 # Protect
627 'protectlogpage' => 'Àkọsílẹ̀ àbò',
628 'protect-expiry-options' => 'wákàtí 2:2 hours,ọjọ́ 1:1 day,ọjọ́ 3:3 days,ọ̀ṣẹ̀ 1:1 week,ọ̀ṣẹ̀ 2:2 weeks,osù 1:1 month,osù 3:3 months,osù 6:6 months,ọdún 1:1 year,láìlópin:infinite', # display1:time1,display2:time2,...
629
630 # Namespace form on various pages
631 'namespace' => 'Orúkọàyè:',
632 'blanknamespace' => '(Gbangba)',
633
634 # Contributions
635 'contributions' => 'Àwọn àfikún ẹnitínṣe',
636 'mycontris' => 'Àwọn àfikún mi',
637 'contribsub2' => 'Fún $1 ($2)',
638 'uctop' => '(lókè)',
639 'month' => 'Láti osù (àti sẹ́yìn):',
640 'year' => 'Láti ọdún (àti sẹ́yìn):',
641
642 'sp-contributions-newbies-sub' => 'Fún àwọn àpamọ́ tuntun',
643 'sp-contributions-blocklog' => 'Àkọsílẹ̀ ìdínà',
644
645 # What links here
646 'whatlinkshere' => 'Ìjápọ̀ mọ́ ojúewé yí',
647 'whatlinkshere-title' => 'Àwọn ojúewé tó jápọ̀ mọ́ "$1"',
648 'whatlinkshere-page' => 'Ojúewé:',
649 'linkshere' => "Àwọn ojúewé wọ̀nyí jápọ̀ mọ́ '''[[:$1]]''':",
650 'nolinkshere' => "Kò sí ojúewé tó jápọ̀ mọ́ '''[[:$1]]'''.",
651 'isredirect' => 'àtúnjúwe ojúewé',
652 'whatlinkshere-links' => '← àwọn ìjápọ̀',
653
654 # Block/unblock
655 'blockip' => 'Dínà oníṣe',
656 'ipbsubmit' => 'Dènà oníṣe yìí',
657 'ipboptions' => '2 wákàtí:2 hours,1 ọjọ́:1 day,3 ọjọ́:3 days,1 ọ̀ṣẹ̀:1 week,2 ọ̀ṣẹ̀:2 weeks,1 osù:1 month,3 osù:3 months,6 osù:6 months,1 ọdún:1 year,láìlópin:infinite', # display1:time1,display2:time2,...
658 'blocklink' => 'dínà',
659 'contribslink' => 'àfikún',
660 'blocklogpage' => 'Àkosílẹ̀ ìdínà',
661
662 # Move page
663 'move-page' => 'Yípò $1',
664 'move-page-legend' => 'Yípò ojúewé',
665 'movearticle' => 'Yípò ojúewé:',
666 'newtitle' => 'Sí àkọlé tuntun:',
667 'move-watch' => 'Mójútó ojúewé yìí',
668 'movepagebtn' => 'Yípò ojúewé',
669 'pagemovedsub' => 'Ìyípò ti já sí rere',
670 'movepage-moved' => '<big>\'\'\'"$1" ti yípò sí "$2"\'\'\'</big>', # The two titles are passed in plain text as $3 and $4 to allow additional goodies in the message.
671 'movedto' => 'tiyípò sí',
672 '1movedto2' => '[[$1]] ti yípò sí [[$2]]',
673 'movelogpage' => 'Àkọsílẹ́ ìyípò',
674 'movereason' => 'Ìdíẹ̀:',
675 'revertmove' => 'dápadà',
676
677 # Namespace 8 related
678 'allmessages' => 'Àwọn ìránṣẹ́ sistẹmu',
679 'allmessagesname' => 'Orúkọ',
680
681 # Tooltip help for the actions
682 'tooltip-pt-userpage' => 'Ojúewé mi',
683 'tooltip-pt-mytalk' => 'Ojúewé ọ̀rọ̀ mi',
684 'tooltip-pt-preferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn mi',
685 'tooltip-pt-watchlist' => 'Àkójọ àwọn ojúewé tí ẹ̀ ún mójútó bóyá wọ́nyí padà',
686 'tooltip-pt-mycontris' => 'Àkójọ àwọn àfikún mi',
687 'tooltip-pt-login' => 'A gbà yín níyànjú kí ẹwọlé, bótilẹ̀jẹ́pẹ́ kò pọndandan.',
688 'tooltip-pt-anonlogin' => 'A gbàyín níyànjú láti wọlé, bótilẹ̀jẹ́pé kò ṣe dandan.',
689 'tooltip-pt-logout' => 'Ìbọ́sódé',
690 'tooltip-ca-talk' => 'Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ nípa ohun inú ojúewé yìí',
691 'tooltip-ca-edit' => 'Ẹ le ṣe àtúnṣe sí ojúewé yìí.
692 Ẹ jọ̀wọ́ ẹ lo bọtini àyẹ̀wò kí ẹ tó fipamọ́.',
693 'tooltip-ca-viewsource' => 'Àbò wà lórí ojúewé yìí.
694 Ẹ le wo àmìọ̀rọ̀ rẹ̀.',
695 'tooltip-ca-protect' => 'Dáàbòbo ojúewé yìí',
696 'tooltip-ca-delete' => 'Pa ojúewé yìí rẹ́',
697 'tooltip-ca-move' => 'Yípò ojúewé yìí padà',
698 'tooltip-ca-watch' => "Ṣ'àfikún ojúewé yìí mọ́ ìmójútó yín",
699 'tooltip-ca-unwatch' => 'Ẹ yọ ojúewé yìí kúrò nínú ìmójútó yín',
700 'tooltip-search' => "Ṣ'àwáàrí nínú {{SITENAME}}",
701 'tooltip-p-logo' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
702 'tooltip-n-mainpage' => 'Ẹ ṣe àbẹ̀wò sí Ojúewé Àkọ́kọ́',
703 'tooltip-n-currentevents' => 'Ìròhìn lọ́wọ́lọ́wọ́',
704 'tooltip-n-recentchanges' => 'Àkójọ àwọn àtúnṣe tuntun nínú wiki.',
705 'tooltip-t-whatlinkshere' => "Àkójọ gbogbo ojúewé wiki tó jápọ̀ s'íbí",
706 'tooltip-t-contributions' => 'Ẹ wo àkójọ àwọn àfikún oníṣe yìí',
707 'tooltip-t-emailuser' => 'Ẹ fi e-mail ránṣẹ́ sí oníṣe yìí',
708 'tooltip-t-upload' => 'Ìrùsókè àwọn faili',
709 'tooltip-t-specialpages' => 'Àkójọ gbogbo àwọn ojúewé pàtàkì',
710 'tooltip-ca-nstab-user' => 'Ẹ wo ojúewé oníṣe',
711 'tooltip-ca-nstab-project' => 'Ẹ wo ojúewé iṣẹ́ọwọ́',
712 'tooltip-ca-nstab-image' => 'Ẹ wo ojúewé faili',
713 'tooltip-ca-nstab-template' => 'Ẹ wo àdákọ náà',
714 'tooltip-ca-nstab-category' => 'Ẹ wo ẹ́ka ojúewé',
715 'tooltip-minoredit' => "Ṣ'àmì sí èyí gẹ́gẹ́ bi àtúnṣe kékeré",
716 'tooltip-save' => 'Àfipamọ́ àwọn àtúnṣe',
717 'tooltip-preview' => 'Àyẹ̀wò àwọn àtúnṣe yín, ẹ jọ̀wọ́ ẹ kọ́kọ́ lo è yí kí ẹ tó fipamọ́!',
718 'tooltip-diff' => 'Ìfihàn àwọn àtúnṣe tí ẹ ṣe sí ìkọ yìí.',
719 'tooltip-compareselectedversions' => 'Ẹ wo ìyàtò láàrin àwọn àtúnṣe tí a ṣàyàn fún ojúewé yìí.',
720 'tooltip-watch' => "Ẹ ṣ'àfikún ojúewé yìí mọ́ ìmójútó yín",
721
722 # Attribution
723 'siteuser' => '$1 oníṣe lórí {{SITENAME}}',
724 'lastmodifiedatby' => 'Igba ti a se atunse si ojuewe yi gbeyin ni $2, $1 by $3.', # $1 date, $2 time, $3 user
725
726 # Media information
727 'show-big-image-thumb' => '<small>Ìtóbi àyẹ̀wò yìí: $1 × $2 pixels</small>',
728
729 # Metadata
730 'metadata' => 'Metadata',
731 'metadata-expand' => 'Àfihàn ẹ̀kúnrẹ́rẹ́',
732 'metadata-collapse' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́',
733
734 # 'all' in various places, this might be different for inflected languages
735 'watchlistall2' => 'gbogbo',
736 'namespacesall' => 'gbogbo',
737 'monthsall' => 'gbogbo',
738
739 # E-mail address confirmation
740 'confirmemail' => "Ṣè'múdájú ojúọ̀nà e-mail",
741 'confirmemail_noemail' => 'Ẹ kò ti to ojúọ̀nà e-mail tó ní bámu nínú [[Special:Preferences|ìfẹ́ràn oníṣe]] yín.',
742 'confirmemail_send' => 'Fi àmìọ̀rọ̀ ìmúdájú ránṣẹ́',
743 'confirmemail_sent' => 'E-mail ti ránṣẹ́ ìmúdájú.',
744 'confirmemail_oncreate' => 'A ti fi àmìọ̀rọ̀ ìmúdájú ránṣẹ́ sí ojúọ̀nà e-mail yín.
745 Àmìọ̀rọ̀ yìí kò pọndandan láti mú yín wọlé, sùgbọ́n ẹ gbọ́dọ̀ mu padà kí gbogbo àwọn ohun inú wiki yìí tó dúró lórí e-mail ó tó lè ṣiṣẹ́.',
746 'confirmemail_loggedin' => 'Ojúọ̀nà e-mail yín ti dájú.',
747 'confirmemail_subject' => 'Ìmúdájú ojúọ̀nà e-mail fún {{SITENAME}}',
748
749 # Watchlist editing tools
750 'watchlisttools-edit' => 'Ìwò àti àtúnṣe ìmójútó',
751
752 # Special:SpecialPages
753 'specialpages' => 'Àwọn ojúewé pàtàkì',
754 'specialpages-group-maintenance' => 'Àwọn ìjábọ̀ ìtọ́jú',
755 'specialpages-group-login' => 'Ìwọlé / ìforúkọ sílẹ́',
756 'specialpages-group-pages' => 'Àkójọ àwọn ojúewé',
757 'specialpages-group-pagetools' => 'Àwọn irinṣẹ́ ojúewé',
758
759 # Special:BlankPage
760 'blankpage' => 'Ojúewé òfo',
761
762 );