0b6d4d3b5931b8fa47a96a7a93271e27214df6e4
[lhc/web/wiklou.git] / languages / messages / MessagesYo.php
1 <?php
2 /** Yoruba (Yorùbá)
3 *
4 * @ingroup Language
5 * @file
6 *
7 * @author Demmy
8 */
9
10 $namespaceNames = array(
11 NS_MEDIA => 'Amóhùnmáwòrán',
12 NS_SPECIAL => 'Pàtàkì',
13 NS_TALK => 'Ọ̀rọ̀',
14 NS_USER => 'Oníṣe',
15 NS_USER_TALK => 'Ọ̀rọ̀_oníṣe',
16 NS_PROJECT_TALK => 'Ọ̀rọ̀_$1',
17 NS_IMAGE => 'Àwòrán',
18 NS_IMAGE_TALK => 'Ọ̀rọ̀_àwòrán',
19 NS_MEDIAWIKI => 'MediaWiki',
20 NS_MEDIAWIKI_TALK => 'Ọ̀rọ̀_mediaWiki',
21 NS_TEMPLATE => 'Àdàkọ',
22 NS_TEMPLATE_TALK => 'Ọ̀rọ̀_àdàkọ',
23 NS_HELP => 'Ìrànlọ́wọ́',
24 NS_HELP_TALK => 'Ọ̀rọ̀_ìrànlọ́wọ́',
25 NS_CATEGORY => 'Ẹ̀ka',
26 NS_CATEGORY_TALK => 'Ọ̀rọ̀_ẹ̀ka',
27 );
28
29 $messages = array(
30 # User preference toggles
31 'tog-underline' => 'Fàlàsí àwọn ijápọ̀:',
32 'tog-justify' => "S'àlàyé gbólóhùn ọ̀rọ̀",
33 'tog-hideminor' => "Bo àtúnse kékékèé mọ́'lẹ̀ nínú àtúnse tuntun",
34 'tog-extendwatchlist' => "Fífẹ̀ ìmójútó láti ṣ'àfihàn gbogbo àtúnṣe tó ṣẹ́lẹ̀",
35 'tog-rememberpassword' => "Sè'rántí ọ̀rọ̀ìpamí mi lórí kọmputa yi",
36 'tog-watchcreations' => "S'àfikún ojúewé tí mo dá mọ́ ìmójútó mi",
37 'tog-watchdefault' => "S'àfikún ojúewé tí mo s'àtúnse mọ́ ìmójútó mi",
38 'tog-watchmoves' => "S'àfikún ojúewé tí mo kó kúrò mọ́ ìmójútó mi",
39 'tog-watchdeletion' => "S'àfikún ojúewé tí mo parẹ́ mọ́ ìmójútó mi",
40 'tog-minordefault' => "Se àmì sí gbogbo àtúnse gẹ́gẹ́ bi kékeré lát'ìbẹ̀rẹ̀.",
41 'tog-previewontop' => "Se àyẹ̀wò kí ẹ tó s'àtúnṣe",
42 'tog-previewonfirst' => "S'àfihàn àgbéwò fún àtúnse àkọ́kọ́",
43 'tog-nocache' => "D'ènà fífi ojúewé pamọ́",
44 'tog-enotifwatchlistpages' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími tí ojúewé tí mò ún mójútó bá yípadà',
45 'tog-enotifusertalkpages' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími tí ojúewé ẹnitínse mi bá yípadà',
46 'tog-enotifminoredits' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími bákannà fún àtúnse kékékèé sí ojúewé',
47 'tog-shownumberswatching' => "S'àfihàn iye àwọn ẹnitínse tí wọn ún mójútó",
48 'tog-watchlisthideown' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe mi nínú ìmójútó',
49 'tog-watchlisthidebots' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe bot nínú ìmójútó',
50 'tog-watchlisthideminor' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe kéékèké nínú ìmójútó',
51 'tog-ccmeonemails' => 'Ìfiránṣẹ́ sími àwọn àwòkọ àwọn e-mail tí mo firánṣẹ́ sí àwọn oníṣe míràn',
52 'tog-showhiddencats' => "Ṣ'àfihàn àwọn ẹ̀ka tó pamọ́",
53
54 'underline-always' => 'Nígbà gbogbo',
55
56 # Dates
57 'sunday' => 'Ọjọ́àìkú',
58 'monday' => 'Ọjọ́ajé',
59 'tuesday' => 'Ọjọ́ìsẹ́gun',
60 'wednesday' => 'Ọjọ́rú',
61 'thursday' => 'Ọjọ́bọ̀',
62 'friday' => 'Ọjọ́ẹtì',
63 'saturday' => 'Ọjọ́àbámẹ́ta',
64 'sun' => 'Àìkú',
65 'mon' => 'Ajé',
66 'tue' => 'Ìṣẹ́gun',
67 'wed' => 'Rú',
68 'thu' => 'Bọ̀',
69 'fri' => 'Ẹtì',
70 'sat' => 'Àbámẹ́ta',
71 'january' => 'January',
72 'february' => 'February',
73 'march' => 'March',
74 'april' => 'April',
75 'may_long' => 'May',
76 'june' => 'June',
77 'july' => 'July',
78 'august' => 'August',
79 'september' => 'September',
80 'october' => 'October',
81 'november' => 'November',
82 'december' => 'December',
83
84 # Categories related messages
85 'pagecategories' => '{{PLURAL:$1|Ẹ̀ka|Àwọn ẹ̀ka}}',
86 'category_header' => 'Àwọn ojúewé nínú ẹ̀ka "$1"',
87 'category-empty' => "''Lọ́wọ́lọ́wọ́ ẹ̀ka yìí kò ní ojúewé tàbí amóhùnmáwòrán kankan.''",
88 'hidden-categories' => '{{PLURAL:$1|Ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀|Áwọn ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀}}',
89 'hidden-category-category' => 'Àwọn ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀', # Name of the category where hidden categories will be listed
90 'listingcontinuesabbrev' => 'tẹ̀síwájú',
91
92 'about' => 'Nípa',
93 'newwindow' => '(yíò sí nínú fèrèsè tuntun)',
94 'cancel' => "Fa'gilé",
95 'qbfind' => 'Wá rí',
96 'qbedit' => 'Àtúnṣe',
97 'qbpageoptions' => 'Ojúewé yi',
98 'qbmyoptions' => 'Àwọn ojúewé mi',
99 'qbspecialpages' => 'Àwọn ojúewé pàtàkì',
100 'moredotdotdot' => 'Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́...',
101 'mypage' => 'Ojúewé mi',
102 'mytalk' => 'Ọ̀rọ̀ mi',
103 'anontalk' => 'Ọ̀rọ̀ fún IP yí',
104 'navigation' => 'Atọ́ka',
105 'and' => 'àti',
106
107 'errorpagetitle' => 'Àsìse',
108 'returnto' => 'Padà sí $1.',
109 'tagline' => "Lát'ọwọ́ {{SITENAME}}",
110 'help' => 'Ìrànlọ́wọ́',
111 'search' => 'Ṣe àwáàrí',
112 'searchbutton' => 'Ṣe àwáàrí',
113 'go' => 'Ó yá',
114 'searcharticle' => 'Ó yá',
115 'history' => 'Ìtàn ojúewé',
116 'history_short' => '
117 Ìtàn',
118 'updatedmarker' => 'jẹ́ títúnṣe lẹ́yìn àbẹ̀wò mi',
119 'printableversion' => 'Títẹ̀ sí ìwé',
120 'permalink' => 'Ìjápọ̀ tíkòníyípadà',
121 'print' => 'Tẹ̀síìwé',
122 'edit' => 'Àtúnṣe',
123 'create' => "Ṣè'dá",
124 'editthispage' => "S'àtúnṣe ojúewé yi",
125 'create-this-page' => "Ṣè'dá ojúewé yìí",
126 'delete' => 'Paarẹ́',
127 'deletethispage' => 'Pa ojúewé yi rẹ́',
128 'protect' => 'Dábòbò',
129 'protectthispage' => 'Dá àbò bo ojúewé yìí',
130 'unprotect' => 'Mú àbò kúrò',
131 'unprotectthispage' => 'Mú àbò kúrò lórí ojúewé yìí',
132 'newpage' => 'Ojúewé tuntun',
133 'talkpage' => 'Kábárawasọ̀rọ̀ nípa ojúewé yi',
134 'talkpagelinktext' => 'Kábárawasọ̀rọ̀',
135 'specialpage' => 'Ojúewé Pàtàkì',
136 'personaltools' => 'Àwọn irinṣẹ́ àdáni',
137 'postcomment' => 'Ṣe àwísọ',
138 'talk' => 'Ìfọ̀rọ̀wérọ̀',
139 'views' => 'Àwọn ìwò',
140 'toolbox' => 'Àpótí irinṣẹ',
141 'userpage' => 'Wo ojúewé oníṣe',
142 'projectpage' => 'Wo ojúewé iṣẹ́ọwọ́',
143 'imagepage' => 'Wo ojúewé amóhùnmáwòrán',
144 'mediawikipage' => 'Wo ojúewé ìránṣẹ́',
145 'templatepage' => 'Wo ojúewé àdàkọ',
146 'viewhelppage' => 'Wo ojúewé ìrànlọ́wọ́',
147 'categorypage' => 'Wo ojúewé ẹ̀ka',
148 'viewtalkpage' => 'Wo ìfọ̀rọ̀wérọ̀',
149 'otherlanguages' => 'Àwọn èdè míràn',
150 'redirectedfrom' => '(Àtúnjúwe láti $1)',
151 'redirectpagesub' => 'Ojúewé àtúnjúwe',
152 'lastmodifiedat' => 'Ọjọ́ tí a ṣe àtunṣe ojúewé yi gbẹ̀yìn ni $2, $1.', # $1 date, $2 time
153 'viewcount' => 'A ti wo ojúewé yi ni {{PLURAL:$1|ẹ̀kan péré|iye ìgbà $1}}.',
154 'protectedpage' => 'Ojúewé aláàbò',
155 'jumptonavigation' => 'atọ́ka',
156 'jumptosearch' => "
157 ṣ'àwáàrí",
158
159 # All link text and link target definitions of links into project namespace that get used by other message strings, with the exception of user group pages (see grouppage) and the disambiguation template definition (see disambiguations).
160 'aboutsite' => 'Nípa {{SITENAME}}',
161 'aboutpage' => 'Project:Nípa',
162 'copyright' => 'Gbogbo ohun inú ibí yi wà lábẹ́ $1.',
163 'copyrightpagename' => '{{SITENAME}} ẹ̀tọ́àwòkọ',
164 'copyrightpage' => '{{ns:project}}:Ẹ̀tọ́àwòko',
165 'currentevents' => 'Ìròhìn nísinsìnyí',
166 'currentevents-url' => 'Project:Ìròhìn nísinsìnyí',
167 'disclaimers' => 'Ikìlọ̀',
168 'disclaimerpage' => 'Project:Ìkìlọ̀ gbogbo',
169 'edithelp' => "Ìrànlọ́wọ́ láti s'àtúnṣe",
170 'edithelppage' => 'Help:Àtúnṣe',
171 'mainpage' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
172 'mainpage-description' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
173 'portal' => 'Èbúté àwùjọ',
174 'portal-url' => 'Project:Èbúté Àwùjọ',
175
176 'badaccess-group0' => "A kò gbàyín l'áyè l'áti ṣe ohun tí ẹ bèrè fún.",
177
178 'ok' => 'OK',
179 'youhavenewmessages' => 'Ẹ ní $1 ($2).',
180 'newmessageslink' => 'ìfọ̀rọ̀ránsẹ́ tuntun',
181 'newmessagesdifflink' => 'àtúnṣe ìgbẹ̀yìn',
182 'youhavenewmessagesmulti' => 'Ẹ ní ìfọ̀rọ̀ránsẹ́ tuntun ni $1',
183 'editsection' => "s'àtúnṣe",
184 'editold' => "s'àtúnṣe",
185 'viewsourceold' => 'wo àmìọ̀rọ̀',
186 'editsectionhint' => 'Abala àtúnṣe: $1',
187 'showtoc' => 'fihàn',
188 'hidetoc' => 'bòmọ́lẹ̀',
189 'thisisdeleted' => 'Wo tàbí múpadà $1?',
190 'viewdeleted' => 'Wo $1?',
191 'restorelink' => '{{PLURAL:$1|àtúnṣe tóparẹ́ kan|àtúnṣe tóparẹ́ $1}}',
192 'site-rss-feed' => '$1 RSS Feed',
193 'site-atom-feed' => '$1 Atom Feed',
194
195 # Short words for each namespace, by default used in the namespace tab in monobook
196 'nstab-main' => 'Àyọkà',
197 'nstab-user' => 'Ojúewé oníṣe',
198 'nstab-media' => 'Ojúewé amóhùnmáwòrán',
199 'nstab-special' => 'Pàtàkì',
200 'nstab-project' => 'Ojúewé iṣẹ́ọwọ́',
201 'nstab-image' => 'Faili',
202 'nstab-mediawiki' => 'Ìfọ̀rọ̀ránsẹ',
203 'nstab-template' => 'Àdàkọ',
204 'nstab-help' => 'Ojúewé ìrànlọ́wọ́',
205 'nstab-category' => 'Ẹ̀ka',
206
207 # Main script and global functions
208 'nosuchaction' => 'Kò sí irú ìgbéṣe báun',
209 'nosuchactiontext' => 'Ìgbéṣe tí URL yìí tọ́kasí kò ní ìdámọ̀ lórí wiki yìí',
210 'nosuchspecialpage' => 'Kò sí irú ojúewé pàtàkì báun',
211 'nospecialpagetext' => "<big>'''Ẹ tọrọ ojúewé pàtàkì tólòdì.'''</big>
212
213 Àkójọ àwọn ojúewé pàtàkì tóbámu wà ní [[Special:SpecialPages|{{int:specialpages}}]].",
214
215 # General errors
216 'error' => 'Àsìṣe',
217 'missingarticle-diff' => '(Ìyàtọ̀: $1, $2)',
218 'filecopyerror' => 'Àwòkọ faili "$1" sí "$2" kò ṣe é ṣe.',
219 'filerenameerror' => 'Àtúnsọlórúkọ faili "$1" sí "$2" kò ṣe é ṣe.',
220 'filedeleteerror' => 'Ìparẹ́ faili "$1" kò ṣe é ṣe.',
221 'directorycreateerror' => 'Ìwé-ìjúwe "$1" kò ṣe é ṣe.',
222 'filenotfound' => 'Kò le é ṣe àwáàrí faili "$1".',
223 'badtitle' => 'Àkọ́lé burúkú',
224 'viewsource' => 'Àfihàn ọ̀rọ̀àmì',
225 'viewsourcefor' => 'fún $1',
226 'protectedpagetext' => 'A ti se àtìpa ojúewé yi. Ẹ kò le se àtúnṣe.',
227 'viewsourcetext' => 'Ẹ lè wo ati ẹ lè se àwòkọ ọ̀rọ̀àmì ojúewé yi:',
228 'ns-specialprotected' => 'Àtúnṣe kò ṣe é ṣe sí àwọn ojúewé pàtàkì.',
229 'titleprotected' => "This title has been protected from creation by [[User:$1|$1]]. The reason given is ''$2''.",
230
231 # Login and logout pages
232 'logouttitle' => 'Ibọsóde oníṣe',
233 'logouttext' => "<strong>Ẹ ti bọ́sọ́de.</strong>
234
235 Ẹ le tẹ̀síwájú sí ní lo {{SITENAME}} láìmorúkọ yín, tàbí kí ẹ [[Special:UserLogin|padà wọlé]] bí ẹnikanan tàbí ẹlòmíràn.
236 Àkíyèsí wípé àwọn ojúewé kan le hàn b'ígbà tójẹ́pé ẹ sì wọlé títí tí ẹ ó fi jọ̀wọ́ àdìmú (cache) browser yín.",
237 'welcomecreation' => "== Ẹ kú àbọ̀, $1! ==
238
239 A ti fi orúkọ yín s'ílẹ̀. Ẹ mọ́ gbàgbé l'áti s'àtúnṣe àwọn ìfẹ́ràn {{SITENAME}} yín.",
240 'loginpagetitle' => 'Ìwọlé oníṣe',
241 'yourname' => 'Orúkọ oníṣe (username):',
242 'yourpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́:',
243 'yourpasswordagain' => 'Tẹkíkọ ọ̀rọ̀ìpamọ́ lẹ́ẹ̀kansí:',
244 'remembermypassword' => "Sè'rántí ọ̀rọ̀ìpamí mi lórí kọmputa yi (cookies)",
245 'loginproblem' => '<b>Ẹ ní ìṣòro láti wọlé.</b><br />Ẹ gbìyànjú lẹ́kan sí!',
246 'login' => 'Ìwọlé',
247 'nav-login-createaccount' => 'Ìwọlé / Ìforúkọ sílẹ̀',
248 'userlogin' => 'Ìwọlé / ìforúkọ sílẹ̀',
249 'logout' => 'Ìbọ́sóde',
250 'userlogout' => 'Ìbọ́sóde',
251 'notloggedin' => "Ẹ kò tí w'ọlé",
252 'nologin' => 'Ṣé ẹ fẹ́ wọlé? $1.',
253 'nologinlink' => 'Ẹ fi orúkọ sílẹ̀',
254 'createaccount' => 'Ẹ fi orúkọ sílẹ̀',
255 'gotaccount' => 'Ṣé ẹ ti ní àpamọ́ tẹ́lẹ̀? $1.',
256 'gotaccountlink' => "Ẹ w'ọlé",
257 'createaccountmail' => 'pẹ̀lú e-mail',
258 'badretype' => 'Àwọn ọ̀rọ̀ìpamọ́ tí ẹ kọ kò jọ ra wọn.',
259 'youremail' => 'E-mail:',
260 'username' => 'Orúkọ oníṣe:',
261 'uid' => 'Nọmba ìdámọ̀ fún ẹnitínṣe:',
262 'yourlanguage' => 'Èdè:',
263 'yournick' => 'Ìtọwọ́bọ̀:',
264 'badsiglength' => 'Ìtọwọ́bọ̀ yín ti gùnjù.
265 Kò gbodọ̀ ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà|àwọn àmìlẹ́tà}} $1 lọ.',
266 'email' => 'E-mail',
267 'loginerror' => 'Àsìṣe ìwọlé',
268 'prefs-help-email-required' => 'E-mail ṣe dandan.',
269 'noname' => 'Ẹ kò tọ́kasí orúkọ oníṣe tó ní ìbámu.',
270 'loginsuccesstitle' => 'Ìwọlé ti yọrí sí rere',
271 'loginsuccess' => "'''Ẹ ti wọlé sínú {{SITENAME}} gẹ́gẹ́ bi \"\$1\".'''",
272 'nosuchuser' => 'Kò sí oníṣe kankan pẹ̀lú orúkọ "$1".
273 Ẹ yẹ lẹ́tà yín wò, tàbí [[Special:Userlogin/signup|kí ẹ s\'èdá àpamọ́ tuntun]].',
274 'nouserspecified' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ tọ́kasí orúkọ oníṣe kan.',
275 'wrongpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tí ẹ kìbọ́ kòtọ́.
276 Ẹ jọ̀wọ́ ẹ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kansí.',
277 'passwordtooshort' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín jẹ́ aláìtọ́ tàbí ó kúrú ju bóṣe yẹ lọ.
278 Kò gbọ́dọ̀ dín ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà kan|àmìlẹ́tà $1}} lọ, kí ó sì yàtọ̀ sí oríkọoníṣe yín.',
279 'mailmypassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun sí e-mail',
280 'noemail' => 'Kò sí àkọsílẹ̀ ojúọ̀nà e-mail fún oníṣe "$1".',
281 'emailauthenticated' => 'Ojúọ̀nà e-mail yín fidájú ní ago $3 ọjọ́ $2.',
282 'emailconfirmlink' => 'Ẹ ṣe ìmúdájú ojúọ̀nà e-mail yín',
283 'accountcreated' => 'Ẹ ti fi orúkọ sílẹ̀',
284 'accountcreatedtext' => "A ti ṣ'èdá àpamọ́ oniṣe fún $1.",
285 'createaccount-title' => 'Ìforúkọ sílẹ̀ fún {{SITENAME}}',
286 'loginlanguagelabel' => 'Èdè: $1',
287
288 # Password reset dialog
289 'resetpass' => 'Àtúntò ọ̀rọ̀ìpamọ́ àpamọ́',
290 'resetpass_header' => 'Àtúntò ọ̀rọ̀ìpamọ́',
291 'resetpass_success' => 'Ìyípadà ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín ti já sí rere! Ẹ̀ ún wọlé lọ́wọ́...',
292
293 # Edit page toolbar
294 'link_sample' => 'Àkọlé ìjápọ̀',
295 'media_tip' => 'Ìjápọ̀ faili',
296
297 # Edit pages
298 'summary' => 'Àkótán',
299 'minoredit' => 'Àtúnṣe kékeré nìyí',
300 'watchthis' => "M'ójútó ojúewé yìí",
301 'savearticle' => 'Ẹ fi pamọ́',
302 'preview' => 'Àyẹ̀wò',
303 'showpreview' => 'Àyẹ̀wò',
304 'showdiff' => 'Àfihàn àwọn àyípadà',
305 'anoneditwarning' => "'''Ìkìlọ̀:''' Ẹ ò tíì wọlé.
306 Á ṣe àkọsílẹ̀ ojúọ̀nà IP yín ninu ìwé àtúnṣe ojúewé yìí.",
307 'blockedtitle' => 'Ìdènà sí oníṣe',
308 'whitelistedittitle' => "Ìwọlé ṣe dandan láti ṣ'àtúnṣe",
309 'whitelistedittext' => "Ẹ gbọ́dọ̀ $1 láti ṣ'àtúnṣe àwọn ojúewé.",
310 'confirmedittitle' => "Ìmúdájú E-mail ṣe dandan láti ṣ'àtúnṣe",
311 'nosuchsectiontitle' => 'Kò sí irú abala báun',
312 'loginreqtitle' => "Ẹ gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ w'ọlé ná",
313 'loginreqlink' => 'ìwọlé',
314 'loginreqpagetext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ $1 láti wo àwọn ojúewé míràn.',
315 'accmailtitle' => 'Ti fi ọ̀rọ̀ìpamọ́ ránṣẹ́.',
316 'accmailtext' => 'A ti fi ọ̀rọ̀ìpamọ́ fún "$1" ránṣẹ́ sí $2.',
317 'newarticle' => '(Tuntun)',
318 'newarticletext' => "Ẹ ti tẹ̀lé ìjápọ̀ mọ́ ojúewé tí kò sí.
319 Láti dá ojúewé yí ẹ bẹ̀rẹ̀ síní tẹ́kọ sí inú àpótí ìsàlẹ̀ yí (ẹ wo [[{{MediaWiki:Helppage}}|ojúewé ìrànlọ́wọ́ ]] fun ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ).
320 T'óbá sepé àsìse ló gbé yin dé bi, ẹ kọn bọ́tìnì ìpadàsẹ́yìn.",
321 'note' => '<strong>Àkíyèsí:</strong>',
322 'session_fail_preview' => '<strong>Àforíjìn! A kò le gbésẹ̀ àtúnṣe yín nítorí ìpòfo data ìsinsìyí.
323 Ẹ jọ̀wọ́ ẹ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan si.
324 Tí kò bá sì tún ṣiṣẹ́, ẹ gbìyànjú láti [[Special:UserLogout|bọ̀sòde]] kí ẹ sì padá wọlé.</strong>',
325 'editing' => 'Àtúnṣe sí $1',
326 'yourdiff' => 'Àwọn ìyàtọ̀',
327 'copyrightwarning' => 'Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kíyèsi wípé gbogbo àwọn àfikún sí {{SITENAME}} jẹ́ bẹ̀ lábẹ́ $2 (Ẹ wo $1 fún ẹkunrẹrẹ).
328 Tí ẹ kò bá fẹ́ kí ìkọọ́lẹ̀ yín ó jẹ́ títúnṣe tàbí kì ó jẹ́ pípìn kiri lọ́ná tí kò wù yín, ẹ mọ́ mù wá síbí.<br />
329 Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín, tàbí ẹ wòókọ láti agbègbè ìgboro tàbí irú ìtìlẹ́yín ọ̀fẹ́ bíi bẹ́ẹ̀.
330 <strong>Ẹ MỌ́ MÚ IṢẸ́ TÓ NÍ Ẹ̀TỌ́ÀWÒKỌ SÍLẸ̀ LÁÌ GBÀṢẸ!</strong>',
331 'template-protected' => '(aláàbò)',
332 'template-semiprotected' => '(aláàbò díẹ̀)',
333 'recreate-deleted-warn' => "'''Ìkìlọ̀: Ẹ̀ ún ṣ'èdá ojúewé tí a ti parẹ́ tẹ́lẹ̀.'''
334
335 Ẹ gbọ́dọ̀ gberò bóyá ó bójúmu láti tẹ̀síwájú pẹ̀lú àtúnṣe ojúewé yìí.
336 Àkọsílẹ̀ ìparẹ́ nìyí fún ìrọ̀rùn:",
337
338 # Account creation failure
339 'cantcreateaccounttitle' => 'Ìforúkọsílẹ̀ kò se é se',
340
341 # History pages
342 'currentrev' => 'Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí',
343 'revisionasof' => 'Àtúnyẹ̀wò ní $1',
344 'revision-info' => "Àtúnyẹ̀wò ní $1 l'átọwọ́ $2",
345 'previousrevision' => '← Àtúnyẹ̀wò tópẹ́ju',
346 'nextrevision' => 'Àtúnyẹ̀wò tótuntunju →',
347 'currentrevisionlink' => 'Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí',
348 'cur' => 'lọ́wọ́',
349 'next' => 'tókàn',
350 'last' => 'tẹ́lẹ̀',
351 'page_first' => 'àkọ́kọ́',
352 'page_last' => 'tógbẹ̀yìn',
353 'deletedrev' => '[tiparẹ́]',
354 'historyempty' => '(òfo)',
355
356 # Revision feed
357 'history-feed-title' => 'Ìtàn àtúnyẹ̀wò',
358 'history-feed-description' => 'Ìtàn àtúnyẹ̀wò fún ojúewé yìí ní orí wiki',
359 'history-feed-item-nocomment' => '$1 $2', # user at time
360
361 # Revision deletion
362 'rev-delundel' => 'fihàn/bòmọ́lẹ̀',
363 'pagehist' => 'Ìtàn ojúewé',
364 'deletedhist' => 'Ìtàn ìparẹ́',
365 'revdelete-summary' => 'àkótán àtúnṣe',
366 'revdelete-uname' => 'orúkọ oníṣe',
367
368 # Diffs
369 'editundo' => 'dápadà',
370 'diff-movedto' => 'tiyípò sí $1',
371
372 # Search results
373 'searchresults' => 'Àwọn èsì àwáàrí',
374 'searchresults-title' => 'Àwọn èsì àwáàrí fún $1',
375 'searchsubtitle' => 'Ẹ ṣ\'àwáàrí fun \'\'\'[[:$1]]\'\'\' ([[Special:Prefixindex/$1|gbogbo ojúewé tó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lu "$1"]] | [[Special:WhatLinksHere/$1|gbogbo ojúewé tó jápọ̀ mọ́ "$1"]])',
376 'searchsubtitleinvalid' => "Ẹ ṣ'àwáàrí fun '''$1'''",
377 'noexactmatch' => "'''Kò sí ojúewé pẹ̀lú àkọlé \"\$1\".'''
378 Ẹ le [[:\$1|ṣ'èdá ojúewé yìí]].",
379 'noexactmatch-nocreate' => "'''Kò sí ojúewé pẹ̀lú àkọlé \"\$1\".'''",
380 'prevn' => 'titẹ́lẹ̀ $1',
381 'nextn' => 'tókàn $1',
382 'viewprevnext' => 'Ẹ wo ($1) ($2) ($3)',
383 'search-relatedarticle' => 'Tóbáramu',
384 'searchrelated' => 'tóbáramu',
385 'searchall' => 'gbogbo',
386 'powersearch' => 'Ṣe àwáàrí',
387 'powersearch-legend' => 'Àwáàrí gíga',
388 'powersearch-ns' => 'Àwáàrí nínú orúkọàyè:',
389 'powersearch-redir' => 'Àkójọ àwọn àtúnjúwe',
390 'powersearch-field' => 'Àwáàrí fún',
391
392 # Preferences page
393 'preferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn',
394 'mypreferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn mi',
395 'prefs-edits' => 'Iye àwọn àtúnṣe:',
396 'prefsnologin' => 'Ẹ kò tíì wọlé',
397 'prefsnologintext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ <span class="plainlinks">[{{fullurl:Special:Userlogin|returnto=$1}} wọlé]</span> láti to àwọn ìfẹ́ràn oníṣe.',
398 'changepassword' => 'Ìyípadà ọ̀rọ̀ìpamọ́',
399 'skin' => 'Skin (Àwọ̀)',
400 'dateformat' => 'Ìṣájúètò ọjọ́',
401 'datedefault' => 'Kò sí ìfẹ́ràn',
402 'datetime' => 'Ọjọ́ àti àkókò',
403 'prefs-personal' => 'Ọ̀rọ̀ nípa oníṣe',
404 'prefs-rc' => 'Àwọn àtúnṣe tuntun',
405 'prefs-watchlist' => 'Ìmójútó',
406 'prefs-watchlist-days' => 'Ọjọ́ láti fihàn nínú ìmójútó:',
407 'saveprefs' => 'Ìfipamọ́',
408 'resetprefs' => 'Palẹ̀mọ́ àwọn àtúnṣe tí kò sì ní ìpamọ́',
409 'oldpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ titẹ́lẹ̀:',
410 'newpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun:',
411 'searchresultshead' => 'Àwáàrí',
412 'savedprefs' => 'Àwọn ìfẹ́ràn yín ti wà nípamọ́.',
413 'prefs-searchoptions' => 'Àwọn ìyàn àwáàrí',
414 'prefs-namespaces' => 'Àwọn orúkọàyè',
415 'files' => 'Àwọn faili',
416
417 # Groups
418 'group' => 'Àkójọpọ̀:',
419 'group-autoconfirmed' => 'Àwọn oníṣe ìmúdájú fúnrawọn',
420 'group-sysop' => 'Àwọn alámùójútó',
421
422 'grouppage-user' => '{{ns:project}}:Àwọn oníṣe',
423 'grouppage-autoconfirmed' => '{{ns:project}}:Àwọn oníṣe ìmúdájú fùnrawọn',
424 'grouppage-bot' => '{{ns:project}}:Àwọn Bot',
425 'grouppage-sysop' => '{{ns:project}}:Àwọn alámùójútó',
426
427 # Recent changes
428 'recentchanges' => 'Àwọn àtúnṣe tuntun',
429 'rcnote' => "Lábẹ́ yìí ni {{PLURAL:$1|àtúnṣe '''kan'''|àwọn àtúnṣe '''$1'''}} tó kẹ̀yìn ní ọjọ́ '''$2''' sẹ́yìn, ní ago $5, ọjọ́ $4.",
430 'rcshowhideminor' => '$1 àwọn àtúnṣe kékéèké',
431 'rclinks' => "Ṣ'àfihàn àtúnṣe $1 tó kẹ̀yìn ní ọjọ́ $2 sẹ́yìn<br />$3",
432 'diff' => 'ìyàtọ̀',
433 'hist' => 'ìtàn',
434 'hide' => 'Ìbòmọ́lẹ̀',
435 'show' => 'Àfihàn',
436 'minoreditletter' => 'k',
437 'newpageletter' => 'T',
438 'boteditletter' => 'b',
439 'rc_categories_any' => 'Èyíkéyìí',
440 'newsectionsummary' => '/* $1 */ abala tuntun',
441
442 # Recent changes linked
443 'recentchangeslinked' => 'Àtúnṣe tó báramu',
444 'recentchangeslinked-title' => 'Àtúnṣe tó báramu mọ́ "$1"',
445 'recentchangeslinked-page' => 'Orúkọ ojúewé:',
446
447 # Upload
448 'upload' => 'Ìrùsókè faili',
449 'uploadbtn' => 'Ìrùsókè faili',
450 'reupload' => 'Àtún-rùsókè',
451 'uploadnologin' => 'Ẹ kò tíì wọlé',
452 'uploadnologintext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ [[Special:UserLogin|wọlè]] láti rùsókè faili.',
453 'uploaderror' => 'Àsìse ìrùsókè',
454 'filename' => 'Ọrúkọ faili',
455 'filedesc' => 'Àkótán',
456 'fileuploadsummary' => 'Àkótán:',
457 'uploadedfiles' => 'Àwọn faili tórùsókè',
458 'ignorewarning' => 'Fojúfo ìkìlọ̀ sì fi faili pamọ́',
459 'ignorewarnings' => 'Fojúfo ìkìlọ̀ tó wù kó jẹ́',
460 'minlength1' => 'Ó kéréjù àwọn orúkọ faili gbọdọ̀ jẹ́ lẹ́tà kan.',
461
462 # Special:ImageList
463 'imagelist_name' => 'Orúkọ',
464 'imagelist_user' => 'Oníṣe',
465
466 # Image description page
467 'filehist' => 'Ìtàn faili',
468 'filehist-current' => 'lọ́wọ́',
469 'filehist-user' => 'Oníṣe',
470 'filehist-comment' => 'Àwísọ',
471 'imagelinks' => 'Àwọn ìjápọ̀',
472 'linkstoimage' => '{{PLURAL:$1|Ojúewé yí|$1 Àwọn ojúewé yí}} jápọ̀ mọ́ àpò yí:',
473
474 # File deletion
475 'filedelete' => 'Paarẹ́ $1',
476 'filedelete-submit' => 'Paarẹ́',
477
478 # MIME search
479 'download' => 'ìrùsílẹ̀',
480
481 'withoutinterwiki' => 'Àwọn ojúewé tí kò ní ìjápọ̀ èdè',
482
483 'fewestrevisions' => 'Àwọn ojúewé pẹ̀lú àwọn àtúnyẹ̀wọ̀ tókéréjù',
484
485 # Miscellaneous special pages
486 'nbytes' => '$1 {{PLURAL:$1|byte|bytes}}',
487 'ncategories' => '{{PLURAL:$1|ẹ̀ka|àwọn ẹ̀ka}} $1',
488 'nlinks' => '{{PLURAL:$1|ìjápọ̀|àwọn ìjápọ̀}} $1',
489 'nrevisions' => '{{PLURAL:$1|àtúnyẹ̀wò|àwọn àtúnyẹ̀wò}} $1',
490 'lonelypages' => 'Àwọn ojúewé aláìlóbìí',
491 'lonelypagestext' => 'Àwọn ojúewé wọ̀nyí kò ní ìjápọ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn ojúewé míràn nínú {{SITENAME}}.',
492 'uncategorizedpages' => 'Àwọn ojúewé aláìlẹ́ka',
493 'popularpages' => 'Ojúewé tógbajúmọ̀',
494 'wantedcategories' => 'Àwọn ẹ̀ka aláìní',
495 'newpages' => 'Àwọn ojúewé tuntun',
496 'newpages-username' => 'Orúkọ oníṣe:',
497 'move' => 'Yípò',
498 'movethispage' => 'Yípò ojúewé yìí',
499
500 # Special:Log
501 'specialloguserlabel' => 'Oníṣe:',
502 'speciallogtitlelabel' => 'Àkọlé:',
503
504 # Special:AllPages
505 'allpages' => 'Gbogbo ojúewé',
506 'alphaindexline' => '$1 $2',
507 'allarticles' => 'Gbogbo ojúewé',
508 'allinnamespace' => 'Gbogbo ojúewé ($1 namespace)',
509 'allnotinnamespace' => 'Gbogbo ojúewé (tí kòsí ní $1 namespace)',
510
511 # Special:Categories
512 'categories' => 'Àwọn ẹ̀ka',
513
514 # E-mail user
515 'emailfrom' => 'Láti:',
516 'emailto' => 'Sí:',
517 'emailsubject' => 'Oríọ̀rọ̀:',
518 'emailmessage' => 'Ìránṣẹ́:',
519 'emailsend' => 'Firánṣẹ́',
520
521 # Watchlist
522 'watchlist' => 'Ìmójútó mi',
523 'mywatchlist' => 'Ìmójútó mi',
524 'watch' => "M'ójútó",
525 'watchthispage' => "M'ójútó ojúewé yi",
526 'unwatch' => "Já'wọ́ ìmójútó",
527 'unwatchthispage' => "Já'wọ́ ìmójútó ojúewé yi",
528
529 # Displayed when you click the "watch" button and it is in the process of watching
530 'watching' => 'Ún mójútó...',
531
532 'enotif_impersonal_salutation' => 'Oníṣe {{SITENAME}}',
533 'changed' => 'tiyípadà',
534 'created' => 'tiṣèdá',
535 'enotif_subject' => '$PAGEEDITOR $CHANGEDORCREATED ojúewé $PAGETITLE lórí {{SITENAME}}',
536
537 # Delete
538 'deletedarticle' => 'A ti pa "[[$1]]" rẹ́',
539
540 # Namespace form on various pages
541 'namespace' => 'Orúkọàyè:',
542 'blanknamespace' => '(Gbangba)',
543
544 # Contributions
545 'contributions' => 'Àwọn àfikún ẹnitínṣe',
546 'mycontris' => 'Àwọn àfikún mi',
547
548 # What links here
549 'whatlinkshere' => 'Ìjápọ̀ mọ́ ojúewé yí',
550 'whatlinkshere-title' => 'Àwọn ojúewé tó jápọ̀ mọ́ "$1"',
551 'whatlinkshere-page' => 'Ojúewé:',
552 'isredirect' => 'àtúnjúwe ojúewé',
553 'whatlinkshere-links' => '← àwọn ìjápọ̀',
554
555 # Block/unblock
556 'ipbsubmit' => 'Dènà oníṣe yìí',
557 'ipboptions' => 'wákàtí 2:wákàtí 2,ọjọ́ 1:ọjọ́ 1,ọjọ́ 3:ọjọ́ 3,ọ̀ṣẹ̀ 1:ọ̀ṣẹ̀ 1,ọ̀ṣẹ̀ 2:ọ̀ṣẹ̀ 2,osù 1:osù 1,osù 3:osù 3,osù 6:osù 6,ọdún 1:ọdún 1,láìlópin:láìlópin', # display1:time1,display2:time2,...
558 'blocklink' => 'dínà',
559 'contribslink' => 'àfikún',
560
561 # Move page
562 'move-page' => 'Yípò $1',
563 'move-page-legend' => 'Yípò ojúewé',
564 'movearticle' => 'Yípò ojúewé:',
565 'newtitle' => 'Sí àkọlé tuntun:',
566 'move-watch' => 'Mójútó ojúewé yìí',
567 'movepagebtn' => 'Yípò ojúewé',
568 'pagemovedsub' => 'Ìyípò ti já sí rere',
569 'movepage-moved' => '<big>\'\'\'"$1" ti yípò sí "$2"\'\'\'</big>', # The two titles are passed in plain text as $3 and $4 to allow additional goodies in the message.
570 'movedto' => 'tiyípò sí',
571
572 # Namespace 8 related
573 'allmessagesname' => 'Orúkọ',
574
575 # Tooltip help for the actions
576 'tooltip-pt-userpage' => 'Ojúewé mi',
577 'tooltip-pt-mytalk' => 'Ojúewé ọ̀rọ̀ mi',
578 'tooltip-pt-preferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn mi',
579 'tooltip-pt-watchlist' => 'Àkójọ àwọn ojúewé tí ẹ̀ ún mójútó bóyá wọ́nyí padà',
580 'tooltip-pt-mycontris' => 'Àkójọ àwọn àfikún mi',
581 'tooltip-pt-login' => 'A gbà yín níyànjú kí ẹwọlé, bótilẹ̀jẹ́pẹ́ kò pọndandan.',
582 'tooltip-pt-anonlogin' => 'A gbàyín níyànjú láti wọlé, bótilẹ̀jẹ́pé kò ṣe dandan.',
583 'tooltip-pt-logout' => 'Ìbọ́sódé',
584 'tooltip-ca-talk' => 'Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ nípa ohun inú ojúewé yìí',
585 'tooltip-ca-edit' => 'Ẹ le ṣe àtúnṣe sí ojúewé yìí.
586 Ẹ jọ̀wọ́ ẹ lo bọtini àyẹ̀wò kí ẹ tó fipamọ́.',
587 'tooltip-ca-protect' => 'Dáàbòbo ojúewé yìí',
588 'tooltip-ca-delete' => 'Pa ojúewé yìí rẹ́',
589 'tooltip-ca-move' => 'Yípò ojúewé yìí padà',
590 'tooltip-ca-watch' => "Ṣ'àfikún ojúewé yìí mọ́ ìmójútó yín",
591 'tooltip-search' => "Ṣ'àwáàrí nínú {{SITENAME}}",
592 'tooltip-p-logo' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
593 'tooltip-n-mainpage' => 'Ẹ ṣe àbẹ̀wò sí Ojúewé Àkọ́kọ́',
594 'tooltip-n-recentchanges' => 'Àkójọ àwọn àtúnṣe tuntun nínú wiki.',
595 'tooltip-t-whatlinkshere' => "Àkójọ gbogbo ojúewé wiki tó jápọ̀ s'íbí",
596 'tooltip-t-upload' => 'Ìrùsókè àwọn faili',
597 'tooltip-t-specialpages' => 'Àkójọ gbogbo àwọn ojúewé pàtàkì',
598 'tooltip-ca-nstab-category' => 'Ẹ wo ẹ́ka ojúewé',
599 'tooltip-save' => 'Àfipamọ́ àwọn àtúnṣe',
600
601 # Attribution
602 'siteuser' => '$1 oníṣe lórí {{SITENAME}}',
603 'lastmodifiedatby' => 'Igba ti a se atunse si ojuewe yi gbeyin ni $2, $1 by $3.', # $1 date, $2 time, $3 user
604
605 # 'all' in various places, this might be different for inflected languages
606 'namespacesall' => 'gbogbo',
607
608 # E-mail address confirmation
609 'confirmemail' => "Ṣè'múdájú ojúọ̀nà e-mail",
610 'confirmemail_noemail' => 'Ẹ kò ti to ojúọ̀nà e-mail tó ní bámu nínú [[Special:Preferences|ìfẹ́ràn oníṣe]] yín.',
611 'confirmemail_send' => 'Fi àmìọ̀rọ̀ ìmúdájú ránṣẹ́',
612 'confirmemail_sent' => 'E-mail ti ránṣẹ́ ìmúdájú.',
613 'confirmemail_oncreate' => 'A ti fi àmìọ̀rọ̀ ìmúdájú ránṣẹ́ sí ojúọ̀nà e-mail yín.
614 Àmìọ̀rọ̀ yìí kò pọndandan láti mú yín wọlé, sùgbọ́n ẹ gbọ́dọ̀ mu padà kí gbogbo àwọn ohun inú wiki yìí tó dúró lórí e-mail ó tó lè ṣiṣẹ́.',
615 'confirmemail_loggedin' => 'Ojúọ̀nà e-mail yín ti dájú.',
616 'confirmemail_subject' => 'Ìmúdájú ojúọ̀nà e-mail fún {{SITENAME}}',
617
618 # Special:SpecialPages
619 'specialpages' => 'Àwọn ojúewé pàtàkì',
620 'specialpages-group-maintenance' => 'Àwọn ìjábọ̀ ìtọ́jú',
621 'specialpages-group-login' => 'Ìwọlé / ìforúkọ sílẹ́',
622 'specialpages-group-pages' => 'Àkójọ àwọn ojúewé',
623 'specialpages-group-pagetools' => 'Àwọn irinṣẹ́ ojúewé',
624
625 # Special:BlankPage
626 'blankpage' => 'Ojúewé òfo',
627
628 );